Bharrat Jagdeo
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Indian
Bharrat Jagdeo tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù Kíní ọdún 1964 jẹ́ ̀Aàrẹ orílẹ̀-èdè Guyana láti ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kẹjọ ọdún 1999. Ó jẹ́ Alákòóso ètò ìṣúná[1] kí ó tó di Ààrẹ lẹ́yìn tí Ààrẹ Janet Jagan kúrò nípò.
Bharrat Jagdeo Junior | |
---|---|
8th President of Guyana | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 August 1999 | |
Alákóso Àgbà | Sam Hinds |
Asíwájú | Janet Jagan |
8th Prime Minister of Guyana | |
In office 9 August 1999 – 11 August 1999 | |
Ààrẹ | Janet Jagan |
Asíwájú | Sam Hinds |
Arọ́pò | Sam Hinds |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kínní 1964 Unity Village, Guyana |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Progressive Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Varshni Jagdeo (Divorced) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Meet the New Cabinet Members", GINA.