Samuel Archibald Anthony Hinds (ojoibi 27 December 1943) je oloselu ara Guyana to je Alakoso Agba ile Guyana lowolowo. Fun igba die o je Aare ile Guyana lati 6 March 1997 de 19 December 1997.

Samuel Archibald Anthony Hinds
Sam Hinds 2006.jpg
5th, 7th, 9th Prime Minister of Guyana
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 August 1999
ÀàrẹBharrat Jagdeo
AsíwájúBharrat Jagdeo
In office
19 December 1997 – 9 August 1999
ÀàrẹJanet Jagan
AsíwájúJanet Jagan
Arọ́pòBharrat Jagdeo
In office
9 October 1992 – 6 March 1997
ÀàrẹCheddi Jagan
AsíwájúHamilton Green
Arọ́pòJanet Jagan
6th President of Guyana
In office
6 March 1997 – 19 December 1997
Alákóso ÀgbàBharrat Jagdeo
AsíwájúCheddi Jagan
Arọ́pòJanet Jagan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kejìlá 1943 (1943-12-27) (ọmọ ọdún 79)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Progressive Party
(Àwọn) olólùfẹ́Yvonne Hinds


ItokasiÀtúnṣe