Bindo Jibrilla
Oloselu Naijiria
Bindo Jibrilla jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.[2]
Bindo Umaru Jibrilla | |
---|---|
Gómìnà ìpínlẹ̀ Adamawa | |
In office 29 May 2015 – 29 May 2019 | |
Asíwájú | Bala James Ngilari |
Arọ́pò | Umaru Fintiri |
Senator for Adamawa North | |
In office Oṣù karún Ọdún 2011 – Oṣù karún Ọdún 2015 | |
Asíwájú | Mohammed Mana |
Arọ́pò | Binta Masi Garba |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Adamawa State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | APC |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Sule Lazarus & Ibrahim Muhammad,Yola (5 December 2010). "Adamawa senators face tough return hurdles". Sunday Trust. Archived from the original on 9 December 2010. Retrieved 23 April 2011.
- ↑ "Adamawa PDP Crisis: Court dismisses Sen. Bent's Suit". Channels TV. 23 March 2011. Archived from the original on 20 July 2011. Retrieved 23 April 2011.