Binos Dauda Yaroe
Olóṣèlú Naijiria
Sen. Binos Dauda Yaroe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè Adamawa South Senatorial District ti Ìpínlẹ̀ Adamawa[1] ní ilé ìgbìmò Aṣòfin àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́.[2][3][4]
Binos Dauda Yaroe | |
---|---|
Sénátọ̀ | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | June 11, 2019 títí di ìsinsìnyí |
Asíwájú | Sen. Ahmed Abubakar Mo'Allahyidi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | January 1, 1955 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Bàbá | Dauda Yaroe |
Profession | Politician |
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Binos Dauda Yaroe ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1955, ní Wagole, abúlé kan ní agbègbè Ribadu Ward ti ìjọba ìbílè Mayo-Belwa ní Ìpínlẹ̀ Adámáwá, Nàìjíríà. Ó fẹ́ Mrs. Gimbiya Joshua, ní ọdún 1983; wọ́n bí ọmọ mẹ́rin.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Senate President Ahmed Lawan praises Binos over impact of medical outreach". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-09. Retrieved 2022-03-18.
- ↑ "PDP Claims Adamawa South Senatorial Seat". aitonline.tv.
- ↑ "APC commands Senate majority with 63 Senators, PDP behind with 44". http. March 12, 2019.
- ↑ "Inconclusive Polls: Who wins Kano, Sokoto, Bauchi, Adamawa, Benue Plateau?". The Nation Newspaper. March 16, 2019. https://thenationonlineng.net/supplementary-pollswho-wins-kano-sokoto-bauchi-adamawa-benue-plateau/.
- ↑ "Nigeria ScoreCard". www.nigeriascorecard.com. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28.