Boerewors-roll
Boerewors-roll jẹ ẹya burẹdi ti wọn maa n fi Boerewors, eyi ti ati yaan daadaa si aarin meji rẹ. O tun maa n pẹlu alubọsa lati fun ounjẹ naa ni adun to dara. O gbajumọ ni orilẹ-ede Guusu Afrika ati awọn agbegbe rẹ.