Mobolaji E. Aluko (tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù Kẹrin 1955) jẹ Ọ̀jọ̀gbọ́n tí ìmọ̀-ẹ̀rọ kẹ́míikálì ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Howard. [1] Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí alábòójútó ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti Yunifásítì Federal, Otuoke nípasẹ̀ ìjoba Àpapọ̀ti Nigeria[2] láti ọdún 2011 títí di ìpárí àkókò iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2016.[3]

Professor
Bolaji Aluko
Ọjọ́ìbíMobolaji E. Aluko
2 Oṣù Kẹrin 1955 (1955-04-02) (ọmọ ọdún 69)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ife
Imperial College London
University of California, Santa Barbara
Iṣẹ́Engineer
Academics
Educational administrator
Ìgbà iṣẹ́1984–present
Gbajúmọ̀ fúnChemical Engineering
Parent(s)Sam Aluko (father)
Àwọn olùbátanGbenga Aluko (brother)

Awọn itọkasi

àtúnṣe