Erékùṣù Ilẹ̀agbègbè Bonaire (pípè /bɒˈnɛər/; Duki: Eilandgebied Bonaire, Papiamento: Teritorio Insular di Boneiru) je ikan ninu is one of five awon erekusu ileagbegbe marun (Eilandgebieden) ti Netherlands Antilles, to ni erekusu gbangba Bonaire ati, ni apaiwoorun re Klein Bonaire. Lapapo mo Aruba ati Curaçao won je awon erekusu ti a mo bi awon Erekusu ABC ti Leeward Antilles, asopo erekusu apaguusu Lesser Antilles.

Erékùṣù Ilẹ̀-agbègbè Bonaire

Eilandgebied Bonaire
Teritorio Insular di Boneiru
Flag of Bonaire
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Bonaire
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Location of Bonaire
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Kralendijk
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaDutch, Papiamento, English
ÌjọbaSee Politics of the Netherlands Antilles
• Lieutenant-Governor of Bonaire
Glenn Thodé
• Governor of N.A.
Frits Goedgedrag
Constitutional monarchy 
Ìtóbi
• Total
294 km2 (114 sq mi)
Alábùgbé
• 2006 census
14,006
• Ìdìmọ́ra
49/km2 (126.9/sq mi) (ranked as part of N. A.)
OwónínáNetherlands Antillean guilder (ANG)
Ibi àkókòUTC-4 (-4)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù599
Internet TLD.an