Catherine Zeta-Jones
Catherine Zeta-Jones, CBE, ( /ˈziːtə/; oruko abiso Catherine Zeta Jones; 25 September 1969) je osere ara Welsi to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo ati Ebun Tony.
Catherine Zeta-Jones | |
---|---|
Zeta-Jones at the 2012 Tribeca Film Festival | |
Ọjọ́ìbí | Catherine Zeta Jones 25 Oṣù Kẹ̀sán 1969 Swansea, Wales, United Kingdom |
Orílẹ̀-èdè | British |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1981–present |
Olólùfẹ́ | Michael Douglas (m. 2000–present) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Igbesi Aye Arabinrin naa
àtúnṣeAbi Catherine si Swansea, Arabinrin naa gbero lati jẹ óṣèrè lobinrin lati kekere nibi ti o ti kopa ninu Akojọpọ west end orin Annie ati Bugsy Malone[1]. Nitoripè Catherine jẹ ọmọ to jafafa, iya rẹ ran lọ si Ilè ẹkọ Hazel Johnson to dale óri ijó nigba ti o pè ọmọ ọdun mẹrin[2]. Óṣèrè lobinrin naa kẹkọ ni Ilẹ iwe Arts ni ilẹ london lori èrè oritage orin ti o si bẹrẹ sini kopa ni èrè oritage ni ọdun 1987 ninu èrè "42nd Street".
Yatọsi jijẹ óṣèrè, arabinrin naa tun kopa ninu riran awọn alaini lọwọ. Óṣere naa jẹ Patron fun Longfields ilu Swansea to da lori awọn akanda. Catherine ta aṣọ ti ó wọ ninu ọkan ninu awọn ere rẹ "Mark of Zorro" lati fi kó òwó jọ fun awọn to ni arun kogbogun AID ni ilẹ Afirica[3]. Zeta naa fẹ óṣere lọkunrin Michael Douglas ti o si bi ọmọ meji[4].
Ami Ẹyẹ ati Idani lọla
àtúnṣeItokasi
àtúnṣe- ↑ https://www.rottentomatoes.com/celebrity/catherine_zetajones
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-08-30. Retrieved 2022-08-30.
- ↑ http://news.bbc.co.uk/2/hi/uk_news/wales/1106741.stm
- ↑ https://web.archive.org/web/20160303181233/http://www.seasonmagazine.com/profiles/czeta-jonesw05.htm
- ↑ https://www.theguardian.com/film/2009/dec/14/catherine-zeta-jones-broadway-musical
- ↑ https://www.ctvnews.ca/mobile/catherine-zeta-jones-honoured-by-queen-elizabeth-ii-1.521713