Chad Basin National Park
Chad Basin National Park(Èdè Yorùbá: ọ̀gbà ìṣeré Chad Basin), jé ọgbà ìṣeré kan ní apá àríwá ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ní Chad Basin, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó tó 2,258 km2. Wọ́n pín ọgbà náà sí mẹ́ta. Apá Chingurmi-Duguma wà ní Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó, ní agbègbè Sudanian Savanna . Àwọn apá Bade-Nguru àti Bulatura wà ní Ìpínlẹ̀ Yòbè ní agbègbè Sahel.[1]
Ìtàn
àtúnṣeChad Basin National Park wà níbi tí ìjọba tẹ́lẹ̀rí, Ìjọba Kanem-Bornu, tí ó wà láàrin ṣẹ́ńtúrì kẹsàn-án sí ṣẹ́ńtúrì ọ̀kàndínlógún tí ó sì wà lára ìpínlè Borno àti Yobo lónìí.
Apá Bade-Nguru Wetlands sector
àtúnṣeBade-Nguru Wetlands jẹ́ apá kan Hadejia-Nguru wetlands, ó sì ní ilẹ̀ tí ó tó 938 km2 ní 12°40′0″N 10°30′0″E / 12.66667°N 10.50000°E. Ó wà ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn Bade àti ìjọba ìbílẹ̀ Jakusko Local ní ìpínlẹ̀ Yobe.
Apá Bulatura
àtúnṣeApá Bulatura wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Yusufari ní ìpínlẹ̀ Yobe, ó sì ní ilẹ̀ tí ó tó 92 km2 around coordinates 13°15′0″N 11°00′0″E / 13.25000°N 11.00000°E.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedNNPS