Charlize Theron
Charlize Theron (General American English pronunciation: /ʃɑrˈliːs ˈθɛrən/; Afrikaans pronunciation: Àdàkọ:IPA-af;[1] ojoibi 7 August 1975) je osere ati ologe aso ara Guusu Afrika[2] to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Todarajulo.
Charlize Theron | |
---|---|
Theron at WonderCon in March 2012 promoting Prometheus. | |
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kẹjọ 1975 Benoni, Transvaal Province, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African and American from 2007 |
Iṣẹ́ | Actress, producer, director, fashion model |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Alábàálòpọ̀ | Stuart Townsend (2001–2010) |
Àwọn ọmọ | Jackson Theron (adopted) |
Website | charlizetheron.com |
Ìbéèrè pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bíi Theron sì ìlú Benoni ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà, òun nìkan sì ni àwọn òbí rẹ bí.[3][4] Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà, ọdún 1991, bàbà Theron tí ó jé ọ̀mùtí gbèrò láti pa Charlize àti ìyá rẹ,[5] o yín ìbon fún wọn, ṣùgbọ́n kò bá wọn, ìyá Charlize bá gbé ìbon tirè ó sì fi pá ọkọ rẹ̀.[6] Ilé ẹjọ́ dá láre, nítorí pé ó fẹ́ pèsè abo fún ohun àti ọmọ rẹ̀.[7][8] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Putfontein Primary school[9][10][11][12] àti National School of Art ni ìlú Johannesburg.[13][14]
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ bere iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníjó, nígbà tí ó wa ni ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, ó gbà iṣẹ́ mọ́dẹ́lì ni ìdíje tí wọ́n ṣe ní Salerno,[15] èyí sì jẹ kó lọ sí ìlú Milan ni orílẹ̀ èdè Italy.[16] Lẹ́yìn tí ó parí iṣẹ́ mọ́dẹ́lì náà, ó lọ sí ilé New York City, níbẹ̀ sì ni ó ti kọ́ bí wọn ṣe jó, àmọ́ ó padà sèse ni orúkún rẹ̀, èyí sì fà á tí kò fi lè jọ mọ́.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Charlize Theron Speaks Afrikaans". YouTube. 30 June 2011. Retrieved 21 March 2012.
- ↑ Farber, Tanya. "Charlize defends her 'unique' American accent". IOL News. http://www.iol.co.za/news/south-africa/charlize-defends-her-unique-american-accent-1.208000. "I am a South African."
- ↑ "Charlize Theron Biography". Hello Magazine. Archived from the original on 25 June 2012. Retrieved 9 August 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Benoni, East Rand". www.sa-venues.com. Archived from the original on 17 June 2012. Retrieved 9 August 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Tron, Gina (26 July 2017). "Charlize Theron Opens Up About Witnessing Mom Shoot And Kill Her Dad". Oxygen. Retrieved 20 April 2019.
- ↑ Tron, Gina (26 July 2017). "Charlize Theron Opens Up About Witnessing Mom Shoot And Kill Her Dad". Oxygen. Retrieved 20 April 2019.
- ↑ "Charlize Theron". BiographyChannel.co.uk. Archived from the original on 8 December 2009. Retrieved 30 November 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Charlize Theron's Family Tragedy - ABC News". Abcnews.go.com. 6 January 2006. Retrieved 1 August 2015.
- ↑ Àdàkọ:Cite AV media
- ↑ Chi, Paul (27 November 2011). "Charlize Theron: I Was Teased By Mean Girls in High School". People. Archived from the original on 29 November 2011. Retrieved 30 November 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àdàkọ:Cite AV media
- ↑ Àdàkọ:Cite AV media
- ↑ "Charlize Theron". AccessHollywood.com. Archived from the original on 25 July 2010. Retrieved 4 April 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Charlize Theron". People. Archived from the original on 1 June 2009. Retrieved 24 October 2009. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Charlize Theron at Salerno "I could fall in love with Allen" (in Èdè Ítálì). Archived from the original on 5 September 2015. Retrieved 8 August 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Higgins, Charlotte (24 August 2006). "Play It Tough". The Guardian (UK). Archived from the original on 4 May 2009. https://web.archive.org/web/20090504152822/http://www.guardian.co.uk/film/2006/aug/24/cuba. Retrieved 23 February 2008.