Chido Onumah

Oníwé-Ìròyín

Chido Onumah (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10 oṣù April, ọdún 1966) jẹ́ akọ̀ròyìn, òǹkọ̀wé àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn. Ó ti ṣiṣẹ́ fún bíi ogún ọdún gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn, òǹkọ̀wé, ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn àti oníṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ghana, Canada, India, Orílẹ̀ èdè America, Caribbean àti Europe. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè PhD nínú ẹ̀kọ́ Communication and Journalism láti Autonomous University of Barcelona, ní UAB, orílẹ̀-èdẹ̀ Spain. Ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ètò ààbò ní orílẹ̀-èdẹ̀ Naijiria ni ó mu tí wọ́ sì tí í mọ́lé nígbà tí ó wà ní páápá ọkọ̀ òfurufú ti Abuja, bí ó ṣe ń ti Spain bọ̀ nítorí ó wọ ẹ̀wù tí wọ́n kọ "we are all Biafrans" sí.[1][2][3]

Chido Onumah
Image of Chido Onumah
Ọjọ́ìbí10 April 1966
Orílẹ̀-èdèNigerian/Canadian
Gbajúmọ̀ fún
  • Journalist
  • Rights Activist
  • Media & Information Literacy Trainer
TitleJournalist and Author
Olólùfẹ́Sola
Àwọn ọmọFemi, Mobolaji, DOTUN and Moyosore

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Onumah kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní University of Calabar, tó wà ní ipinle Cross River, ní orílẹ̀-èdè Naijiria, ó sì gba M.A nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn láti University of Western Ontario, ní London, Ontario, Canada. Ó tún gba PhD kan nínú ẹ̀kọ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti iṣẹ́ ìròyìn[4] láti Autonomous University of Barcelona, UAB, Spain.

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Onumah ṣiṣẹ́, ó sì kọ̀wé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà bíi; ìwé-ìròyìn Sentinel, Guardian, AM News, PM News, The News/Tempo, Concord, Punch àti Thisday newspaper, kí oh tó lọ sí Accra, ní orílẹ̀-èdè Ghana, ní ọdún 1996. Ó sìn gẹ́gẹ́ bíi olùṣàtúnṣe alábàáṣiṣẹ́pọ̀ ti ìwé-ìròyìn Insight, olùrànlọ́wọ́ olùṣàtúnṣe ìwé-ìròyìn Third World Network African Agenda, olùṣekòkáárí, West African Human Rights Committee àti correspondent fún ìwé-ìròyìn African Observer, New York, àti AfricaNews Service, Nairobi, Kenya.[5]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà

àtúnṣe
  • 2017: Devatop Anti-Human Trafficking Ambassador, Nigeria.[6]
  • 2002: The Jerry Rogers Writing Award, University of Western Ontario, Canada
  • 2001: William C. Heine Fellowship for International Media Studies, University of Western Ontario, Canada
  • 2001: Alfred W. Hamilton Scholarship - Canadian Association of Black Journalists
  • 1999: Kudirat Initiative for Democracy KIND Award for excellence in journalism (Nigeria)
  • 1997: Clement Mwale Prize for courage in journalism, AFRICANEWS SERVICE (Kenya)

Ìwé àtẹ̀jáde

àtúnṣe

Onumah jẹ́ òǹkọ̀wé, ó sì ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé bíi:

  • "Remaking Nigeria: Sixty Years, Sixty Voices"[7] (ed.)
  • "Testimony to Courage: Essays in Honour of Dapo Olorunyomi (with Fred Adetiba)",[8] (ed.)
  • "We Are All Biafrans[9][10] (2016),
  • Nigeria is Negotiable[11] (2013) àti
  • Time to Reclaim Nigeria[12] (Essays 2001-2011) 2011.

O ti satunkọ awọn iwe lori orisirisi wonyen, pẹlu

  • Making Your Voice Heard: A Media Toolkit for Children & Youth (2004);
  • Anti-Corruption Advocacy Handbook (with Comfort Idika-Ogunye) 2006;
  • Youth Media: A Guide to Literacy and Social Change (with Lewis Asubiojo) 2008;
  • Understanding Nigeria and the New Imperialism (with Biodun Jeyifo, Bene Madunagu, and Kayode Komolafe) 2006;
  • Sentenced in God’s Name: The Untold Story of Nigeria’s "Witch Children" (with Lewis Asubiojo) 2011; àti
  • Media and Information Policy and Strategy Guidelines (with Grizzle, A., Moore, P., Dezuanni, M., Asthana, S., Wilson, C. and Banda, F.).[13]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. JournAfrica!. "Chido Onumah". JournAfrica!. Archived from the original on 3 October 2016. Retrieved 30 September 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. International Reporting Project. "Fellows: Chido Onumah". International Reporting Project. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 30 September 2016. 
  3. Adedigba, Azeezat (29 September 2019). "UPDATED: SSS arrests Nigerian activist Chido Onumah". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/355058-breaking-sss-arrests-nigerian-activist-chido-onumah.html. Retrieved 2 October 2019. 
  4. "chido onumah bags Phd from university of autonomous". GlobalNoticeHub (Gloablnotice Hin). 23 September 2019. Archived from the original on 23 September 2019. https://web.archive.org/web/20190923201549/https://www.globalnoticehub.com/chido-baggs-phd/. Retrieved 23 September 2019. 
  5. International Reporting Project. "Fellows: Chido Onumah". International Reporting Project. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 30 September 2016. 
  6. ICIR, Nigeria (2 March 2017). "Football Star, Popular Actor Among Anti-Human Trafficking Ambassadors". ICIR Nigeria. ICIR Nigeria. https://www.icirnigeria.org/football-star-popular-actor-among-anti-human-trafficking-ambassadors/. Retrieved 29 December 2017. 
  7. Chido, Onumah (5 December 2020). Remaking Nigeria, Sixty Years, Sixty Voices. ISBN 978-1953967022. 
  8. Chido, Onumah (27 May 2019). Testimony to Courage: Essays in Honour of Dapo Olorunyomi. ISBN 978-9785443189. 
  9. "We Are All Biafrans is not about Biafra agitation, says author - OAK TV". oak.tv. Oak TV (Oak TV). Archived from the original on 13 January 2017. https://web.archive.org/web/20170113162809/https://oak.tv/weareallbiafrans-not-biafra-agitation-says-author/. Retrieved 11 January 2017. 
  10. Onumah, Chido (29 May 2016). We Are All Biafrans (1st ed.). Lagos: Parrésia Publishers Ltd. ISBN 978-9785407983. 
  11. Onumah, Chido (15 August 2013). Nigeria is Negotiable (1st ed.). Abuja: African Centre for Media & Information Literacy (AFRICMIL). ISBN 978-9789324767. 
  12. Onumah, Chido (15 December 2011). Time to Reclaim Nigeria. Abuja: AFRICMIL. ISBN 978-9789192403. 
  13. Amazon. "Chido Onumah". Amazon. Retrieved 30 September 2016.