Chief Temitope Ajayi
Amina Temitope Ajayi (aka Mama Diaspora) jẹ́ Ọmọ Nàìjíríà tí ó ń gbé ní US, àjùmọ̀sọ̀rọ̀ òwò tí ó ń kọ́ ìṣìrò, on tàjà àwùjọ àti alákòóso aláápọn àgbègbè. Tèmítọ́pẹ́ Àjàyí fi ìgbà kan jẹ́ Ààrẹ gbogbo Nigerian American Congress (ANAC).[1] Akitiyan rẹ̀ àti itẹ̀síwájú àgbàwí lórí í Nigerian Diaspora àríyànjiyàn ti fun ní àkọ́lé ti moniker "Mama Diaspora".[2][3][4][5][6] Chief Àjàyí jẹ́ mímọ̀ gidi nípa ṣíṣe ìgbéga a ìṣe-ìkúnnilágbára àwọn obìnrin àti mímú ìyà dópin ní Ilè adúláwọ̀ látara Agri-business. Látara ìdókòwò o Arkansas-Nigeria fórànmù àti àwọn fórànmù ìpínsíméjì ọ̀rọ̀ ajé ní US, ìdúróṣinṣin àti òdodo o Chief Ajayi ti jẹ́ ohun-èlò ìdánilójú tí ó ń fa ọ̀pọ̀ àwọn olókòwò sínu agri-business láti US sí Nigeria.[7] Ó jẹ́ Olùdásílẹ̀ ẹ Nigerian American Agricultural Empowerment Program (NAAEP), tí ó kọ́ni ní Agricultural empowerment of farmers, àwọn obìnrin àti ọ̀dọ́ ní Nàìjíríà láti fi lè fi kún oúnjẹ lọ̀pọ́ àti láti ṣàkóso iṣẹ́ fún àwọn obìnrin àti àwọn ọ̀dọ́ nínu ẹ̀ka iṣẹ́ àgbẹ̀.[8] NAAEP ni ìpìlẹ̀ Ilé-iṣẹ́ tí ó ń kọ́ àwọn àgbẹ̀ ní 'mechanized farming system', bí ó tí ń dẹ̀rọ̀ ìṣòwò-àwìn, accessibility àyẹ̀wò sí ṣíṣe iṣẹ́ àgbẹ̀, ìkórẹ̀ àti ìpolówó o ọjà wọn nílẹ̀ yí àti lókèèrè.[9][10] Ní ọdún 2010, Chief Àjàyí kàn sí Ìjọba àpapò orílè-èdè Nàìjíríà láti dín owó èlé lórí í àwọn iṣẹ́ àgbẹ̀ kí Wọ́n lè yára sí ẹ̀ka iṣẹ́ àgbẹ̀ àti láti dín ìyà kù nínú orílẹ̀-èdè yìí.[11] Chief Tèmítọ́pẹ́ Àjàyí jẹ́ aṣojú ìjọba ti Goodwill fún ìpínlẹ̀ ẹ Arkansas àti Maryland, USA. Chief Ms. Àjàyí jẹ́ àṣàyàn aṣojú fún 2014 Nigeria's National Conference ní bi tí ó ti jẹ́ aṣojú fún National Council of Women Societies (NCWS) ní Nàìjíríà ó tún ṣiṣẹ́/sìn ní ìgbìmò ọ Confab's Agriculture.[12][13][14][15] Nínú àdírẹ́sì i Chief Tèmítọ́pẹ́ Àjàyí nínu ìpàdé ọdọọdún ti World Bank Group àti International Monetary Fund, ó jẹ́ mímọ̀ pé “Àwọn obìnrin ni ẹ̀ka agbára aláàdáni, àwọn obìnrin ló ń ṣètò ìṣúná owó ní èyíkéyìí orílè-èdè nítorí pé wọ́n mọ̀ nípa è dáadáa ju àwọn ọkùnrin lọ”.[16]
Chief Amina Temitope Ajayi | |
---|---|
aka Mama Diaspora | |
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Accountancy |
Iṣẹ́ | Founder & CEO of NAAEP |
Àwọn ọmọ | Lilian Ajayi-Ore; Denise Ajayi-Williams; Sean Oluwaseun Ajayi; Tiffany Titilope Ajayi; Kevin Olugbenga Labinjo Ajayi |
Parent(s) |
|
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "All Nigerian American Congress (ANAC) was invited to join the Nigerian delegation on behalf of Nigerian diaspora at the United Nations on going summit in New York". Transatlantic Times. Archived from the original on 10 June 2015. Retrieved 6 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "How I Came To Be Known As Mama Diaspora– Ajayi". Leadership. Retrieved 6 June 2015.
- ↑ Sunday Oguntola, "Sweet home-coming", "The Nation", 7 June 2015.
- ↑ "I rarely attend parties, but when I do, I'm there to dance –Temitope Ajayi". The Punch. Archived from the original on 14 June 2015. Retrieved 12 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Temitope Ajayi: Nigerians in Diaspora Are Too Economically Important to be Denied Voting Rights". THIS DAY LIVE. Archived from the original on 10 June 2015. Retrieved 6 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Diaspora Commission will break Nigeria's development jinx — Chief Temitope Ajay". Vanguard. Retrieved 6 June 2015.
- ↑ "Little Rock Hosts Arkansas-NED Forum" (PDF). National Universities Commission. Archived from the original (PDF) on 11 June 2015. Retrieved 10 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria: Developing the Economy Through Farming". AllAfrica.
- ↑ "Nigerian American Agricultural Empowerment Programme (NAAEP)". NAAEP.biz. Archived from the original on 1 August 2015. Retrieved 10 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria: Naaep Signs MOU With Lisabi Mills on Food Production". Vanguard. Retrieved 10 June 2015.
- ↑ "NAEEP reduces interest rate to farmers". Vanguard. Retrieved 5 June 2015.
- ↑ "Presidency Clears 492 Delegates For Confab, Appoints 3 Assistance Secretaries". Nigerian Watch. Archived from the original on 11 June 2015. Retrieved 10 June 2015.
- ↑ "Jonathan has touched Nigerian women — Ajayi Mama Diaspora". Vanguard. Retrieved 6 June 2015.
- ↑ "Confab delegate wants more women in government under Buhari". NAN. Archived from the original on 11 June 2015. Retrieved 10 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Conference Releases List of Committees, Membership". This Day Live. Archived from the original on 17 November 2015. Retrieved 14 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "THE STATUS OF WOMEN AND GIRLS IN AFRICA AND THE REST OF THE WORLD". Diplomatic Courier. Archived from the original on 14 June 2015. Retrieved 12 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)