Chioma Wogu
Success Chioma Wogu (tí wọ́n bí ní 28 January 1999) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó ń gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Yanga Princess ní Tanzanian Women's Premier League.[2] Ó fìgbà kan gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ FC Minsk ní Belarusian Premier League. Bákan náà ni ó farahàn ní Nigeria women's national football team ní ìdíje gbogboogbò. Ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ ní Africa Women Cup of Nations, nígbà tó wà lọ́mọdún mẹ́tàdínlógún (17).[3]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Success Chioma Wogu | ||
Ọjọ́ ìbí | 28 Oṣù Kínní 1999 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ibadan, Nigeria | ||
Playing position | Forward | ||
Club information | |||
Current club | Yanga Princess | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Confluence Queens | (6) | ||
2016–2020 | Rivers Angels[1] | ||
2020–2022 | FC Minsk | 8 | (4) |
2022 | Yanga Princess | ||
National team‡ | |||
2016- | Nigeria | 1 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeWogu jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó ju ọ̀pọ̀ bọ́ọ̀lù wọlé fún Confluence Queens ní 2014 Nigeria Women Premier League, èyí tó jé ìgbà àkókó rẹ̀ nínú eré náà.[4] Ní àsìkò ìdíje 2017 Nigeria Women Premier League láàárín ẹgbẹ́ Rivers Angels àti Heartland Queens, Wogu gbá bọ́ọ̀lù kan wọlé, èyí tó sì mú kí ẹgbẹ́ rẹ̀ gba ipò kìíní.[5][6]
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó wà lára àwọn tó pegedé fún eré Nàìjíríà fún 2014 African Women's Championship, àkọ́nimọ̀ọ́gbá wọn, ìyẹn Edwin Okon yọ Wogu kúrò nínú ìdíje àṣekágbá.[7] Àmọ́ ní ọdún 2016, ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà, ó sì bá wọn gbá bọ́ọ̀lù ní ìtako pẹ̀lú Mali.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Rivers Angels set to unveil new recruits". National Daily NG. 4 February 2016. https://nationaldailyng.com/rivers-angels-set-to-unveil-new-recruits/. Retrieved 23 December 2018.
- ↑ "Tanzania Side unveil three Nigeria Players". 2022-09-05. Archived from the original on 2022-10-01. Retrieved 2024-03-28.
- ↑ 3.0 3.1 "Super Falcons will not underrate Ghana, says Chioma Wogu". Goal.com. Archived from the original on 25 November 2016. Retrieved 2017-08-08. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Chioma Wogu Targets Success With Super Falcons". All Nigeria Soccer. March 2015. Retrieved 2017-08-08.
- ↑ "Wogu And Aku Shoot Angels Back On Top". Ladies March. 2017. Retrieved 2017-08-08.
- ↑ "IBOM Angels end Rivers 100% home run". 2017. Retrieved 2017-08-08.
- ↑ "SL10 Chats To Chioma Wogu". sl10.ng. November 2014. Archived from the original on 17 August 2017. Retrieved 2017-08-08. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)