Edwin Edem Okon[1] (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1970[2]) jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin Rivers Angels. Wọ́n bí I ní Ìpínlẹ̀ Cross River, Okon gba ìwé-ẹ̀rí akọ́nimọ̀ọ́gbá láti ilé-ẹ̀kọ́ eré-ìdárayá kan ni Ìpínlẹ̀ Èkó.[2] Lẹ́yìn tí Kadiri Ikhana, akọ́nimọ̀ọ́gbá àwọn ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-bìnrin Nigeria kọ̀wé fipò sílẹ̀, nítorí tí wọ́n fìdírẹmi nínú ìdíje àwọn agbábọ́ọ̀lù-bìnrin àgbà ti ọdún 2012, 2012 African Women's Championship, wọ́n yàn Okon sípò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá fìdíhẹẹ́ fún ọkọ̀ Super Falcons lọ́dún 2013.[3]

Edwin Okon
Personal information
OrúkọEdwin Edem Okon
Ọjọ́ ìbí19 Oṣù Kẹ̀wá 1970 (1970-10-19) (ọmọ ọdún 54)
Ibi ọjọ́ibíCross River State
Club information
Current clubRivers Angels F.C. (Head Coach)
Teams managed
Nigeria (assistant)
2012Nigeria U20 (Head Coach)
?–presentRivers Angels (Head Coach)
2013–2015Nigeria (Head Coach)

Wọ́n gbaṣẹ́ náà lọ́wọ́ Okon nígbà tí ọkọ̀ [Super Falcons]] Nigeria kò lè tẹ̀ síwájú sí abala fìdírẹmi-o-kúrò 2015 FIFA Women's World Cup, tí àjọ Nigeria Football Federation sìn fi Christian Danjuma, Igbákejì rẹ̀ rọ́pò rẹ̀ ní ipò fìdíhẹẹ́.[4]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

àtúnṣe

àṣeyọrí abẹ́lé

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí Akọ́nimọ̀ọ́gbá Rivers Angels F.C.

Ìdíje àgbábuta líìgì

àtúnṣe

Ìdíje Ife

àtúnṣe
  • 2012 Federation Cup – Ó gba ife-ẹ̀yẹ [12][13]
  • 2013 Nigeria Women Federation Cup – Ó gba ife-ẹ̀yẹ [14]
  • 2014 :Nigeria Women Federation Cup' – Ó gba ife-ẹ̀yẹ[15]
  • 2016 Nigeria Women Federation Cup – Ó gba ife-ẹ̀yẹ [16][17]

Ìdíje pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. admin (24 November 2014). "EXCLUSIVE: Interview With Edwin Edem Okon". sl10.ng. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. 2.0 2.1 admin (4 September 2013). "WHO IS EDWIN OKON? FIND OUT". Savidnews.com. 
  3. Oludare, Shina (21 August 2013). "Edwin Okon appointed [[Super Falcons]] caretaker head coach". Goal.com.  URL–wikilink conflict (help)
  4. Dede, Steve (29 June 2015). "NFF fire Super Falcons coach". Pulse.ng. 
  5. Asaolu, Tolu (27 November 2012). "Women Super Six: Delta Queens face Rivers for final". futaa.com. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. Ologunro, Lukman (6 December 2012). "Delta coach slams Rivers Angels counterpart". Futaa.com. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. Njoku, Humphrey (19 July 2013). "Rivers dream for double intact". Supersport.com. 
  8. Ahmadu, Samuel (27 November 2014). "Rivers Angels are Nigeria women league champions". Goal.com. 
  9. admin (1 September 2015). "Women League Warns Rivers Angel Boss, Edwin Okon; Rewards Precious Edewor". allnigeriasoccer.com. 
  10. Ahmadu, Samuel (6 November 2015). "Rivers Angels retain Nigeria Women Premier League title". Goal.com. 
  11. Inyang, Ifreke (24 January 2017). "Okon excited after Rivers Angels clinch third consecutive NPWL title". Daily Post. https://dailypost.ng/2017/01/24/okon-excited-rivers-angels-clinch-third-consecutive-npwl-title/. Retrieved 24 August 2019. 
  12. admin (19 June 2014). "Celebrating Edwin Okon". sl10.ng. 
  13. admin (18 September 2013). "Rivers Angels Retire Federation Cup Trophy …Enyimba Douses Wolves’ Ambition". thetidenewsonline.com. 
  14. Adebowale, Segun (15 September 2013). "Rivers Angels win 2013 Federation Cup". theeagleonline.com.ng. 
  15. Ahmadu, Samuel (25 November 2014). "Oshoala, Nwabuoku attribute Rivers Angels victory to hard work". Goal.com. 
  16. Asaolu, Tolu (13 September 2016). "Fed Cup: We deserve to win- Okon". futaa.com. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  17. "Federation Cup: Rivers Angels book final berth". vanguardngr.com. 2016.