Chris Abani
Christopher Abani (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1966) jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Christopher Abani je omo bibi ipinle ebonyi
Chris Abani | |
---|---|
Abani in 2007 | |
Ọjọ́ìbí | Christopher Abani 27 December 1966 (ọmọ ọdún 57) Afikpo, Ebonyi State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Author, poet, professor |
Website | chrisabani.com |
Ètò-èkó àti Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeAbani gba ìwé-ẹ̀rí B.A nínú English and Literary Studies ní Fásitì ti ìpínlẹ̀ Imo, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, M.A nínú Gender and Culture ní Birkbeck College, University of London, M.A nínú Imo-ede Geesi ní University of Southern California, àti Ph.D nínú Creative Writing and Literature ní University of Southern California. Abani ti gba àmì ẹ̀yẹ PEN/Barbara Goldsmith Freedom to Write Award, Prince Claus Awards ti ọdún 2001, Lantern Literary Fellowship, California Book Award, Hurston-Wright Legacy Award àti Hemingway Foundation/PEN Award. Díẹ̀ nínú àwọn ewì rẹ̀ jáde nínú jọ́nà kan lórí ẹ̀rọ ayárabíáṣàá Blackbird. Láti ọdún 2007 sí ọdún 2012, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti Creative Writing ní University of California, Riverside. Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Northwestern University.[1] Ìwé ewì rẹ̀ Sanctificum (Copper Canyon Press, ní ọdún 2010), jẹ́ àkójọ ewì tí ó dá lórí ẹbọ ẹ̀sìn, ìfẹ́.[2]
Ààtò àwọn ìwé tí ó ti tẹ̀
àtúnṣeNovels
- Masters of the Board (Delta, 1985)
- GraceLand (FSG, 2004/Picador 2005)
- The Virgin of Flames (Penguin, 2007)
- The Secret History of Las Vegas (Penguin, 2014)
Novellas
- Becoming Abigail (Akashic Books, 2006)
- Song For Night (Akashic Books, 2007)
Poetry
- Kalakuta Republic (Saqi, 2001).
- Daphne's Lot (Red Hen Press, 2003)
- Dog Woman (Red Hen Press, 2004)
- Hands Washing Water (Copper Canyon Press, 2006)
- There are no names for red (Red Hen Press, 2010)
- Feed me the sun (Peepal Tree Press, 2010)
- Sanctificum (Copper Canyon Press, 2010)
Essays
- The Face (Restless Books, 2014)
Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ tí ó gbà
àtúnṣe2001
- PEN USA West Freedom-to-Write Award, US
- Prince Claus Awards.
- Middleton Fellowship, University of Southern California, US
2002
- Imbongi Yesizwe Poetry International Award, South Africa.
2003
- Lannan Foundation Literary Fellowship, US
- Hellman/Hammet Grant from Human Rights Watch, US
2005
- Winner, Hemingway Foundation/PEN Award. (GraceLand)
- Winner, Hurston-Wright Legacy Award (GraceLand)
- Silver Medal, California Book Award for Fiction (GraceLand)
- Finalist, Los Angeles Times Book Prize for Fiction (GraceLand)
- Finalist, Commonwealth Writers Prize, Best Books (Africa Region)(GraceLand)
- Pushcart Nomination for Blooding. StoryQuarterly.
2006
- A New York Times Editor's Choice (Becoming Abigail)
- A Chicago Reader Critic's Choice (Becoming Abigail)
- A selection of the Essence Magazine Book Club (Becoming Abigail)
- A selection of the Black Expressions Book Club (Becoming Abigail)
- Pushcart Nomination (poetry) (A Way To Turn This To Light)
- Shortlisted for International Dublin Literary Award (GraceLand).
2007
- The New York Times Editor's Choice (Song for Night)
- Finalist, PEN/Beyond Margins Award (Becoming Abigail)
- A Barnes & Noble Discovery Selection (The Virgin of Flames)
- A New York Times Editor's Choice (The Virgin of Flames)
- A New York Libraries Books For Teens Selection (Becoming Abigail)
2008
- Winner, PEN/Beyond Margins Award for Song For Night
- Nominated for Lamada Award (The Virgin of Flames)
- Recipient, Distinguished Humanist Award (UC, Riverside)
- 2007 Pushcart Nomination for Sanctificum (poetry)
2009
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Northwestern Announces Professorships" Archived 28 September 2015 at the Wayback Machine., Northwestern University, 27 June 2013.
- ↑ Sanctificum. Copper Canyon Press.