Chris Ngige
Olóṣèlú
Christian Nwabueze Ngige (bíi ní Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹjọ Ọdún 1952) jẹ́ gómìnà Ipinle Anambra, Nàìjíríà láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Odún 2003 di Ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kẹta Odún 2006 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1] Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC.[2]
Chris Nwabueze Ngige | |
---|---|
Aṣojú àárín Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Odún 2003 – Ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kẹta Odún 2006 | |
Asíwájú | Chinwoke Mbadinuju |
Arọ́pò | Peter Obi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹjọ Ọdún 1952 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress, APC. |
Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe
- ↑ Jide Ajani; EmmanuelL Aziken (13 February 2011). "ntrigues stall Ribadu’s choice of running mate". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2011/02/intrigues-stall-ribadu%E2%80%99s-choice-of-running-mate/. Retrieved 14 February 2011.
- ↑ Nwanosike Onu (2011-04-28). "How Ngige floored Akunyili in Anambra Central". The Nation. Retrieved 2011-04-27.