Odumegwu Ojukwu

Olóṣèlú àti ológun ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu)

Chukwuemeka Odumegwu-Ojukwu (a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933[1] - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001)jẹ́ ológun àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ [2]. Ó fìgbà kan jẹ Gómìnà ológun apá àríwá Nàìjíríà lọ́dún 1966. Oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé Biafra fi tako ìjọba orile-ede Nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1970[3].

General C. Odumegwu Ojukwu
Àwòrán Odumegwu Ojukwu
President of Biafra
In office
30 May 1967 – 8 January 1970
Vice PresidentPhilip Effiong
AsíwájúPosition created
Arọ́pòPhilip Effiong
ConstituencyBiafra
Governor of Eastern Region, Nigeria
In office
19 January 1966 – 27 May 1967
AsíwájúFrancis Akanu Ibiam
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1933-11-04)4 Oṣù Kọkànlá 1933
Zungeru, Nigeria
Aláìsí26 November 2011(2011-11-26) (ọmọ ọdún 78)
United Kingdom
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNigerian Military, Biafra military, later APGA
(Àwọn) olólùfẹ́Bianca Ojukwu
Alma materLincoln College, Oxford University
ProfessionSoldier, politician

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ojukwu's birthday". 
  2. "Ojukwu's death announced". Archived from the original on 2011-11-27. Retrieved 2011-11-26. 
  3. "Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu Facts". Biography. 1967-05-30. Retrieved 2019-10-06.