Philip Effiong

Olóṣèlú

Philip Efiong (also spelled Effiong, November 18, 1925 – November 6, 2003) je omo ologun to tifeyinti lati Ile-ise Ajagun Oripapa Naijiria ati ikan ninu awon asagun orile-ede Biafra alaisimo nigba Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà nigba to di Igbakeji Aare ile Biafra si Odumegwu Ojukwu ati Aare ile Biafra fun ojo marun leyin ti Ojukwu salo. Efiong ni eni ti o teriba Biafra fun Naijiria.

Obong Philip Efiong
Aare ile Biafra 2k
In office
January 8, 1970 – January 12, 1970
AsíwájúChukwuemeka Odumegwu Ojukwu
Igbakeji Aare ile Biafra 1k
In office
May 30, 1967 – January 8, 1970
ÀàrẹChukwuemeka Odumegwu Ojukwu
AsíwájúPosition created
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíNovember 18, 1925
Akwa-Ibom State, British West Africa
AláìsíNovember 6, 2003
Aba, Abia State
Ọmọorílẹ̀-èdèNigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Josephine Effiong