Cloris Leachman

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Cloris Leachman ni a bini óṣu April, ọdun 1926 to si ku ni Óṣu january, ọdun 2021. Cloris jẹ óṣèrè lóbinrin ati alawada to si ṣiṣẹ fun ọgọrin ọdun[1].

Cloris Leachman

Igbèsi Àyè Arabinrin naa

àtúnṣe

Leachman ni a bi fun Cloris ati Berkeley Claiborne si ilu Des Moines, Iowa[2].

Cloris gba ẹkọ ọfẹ lati kẹẹkọ ni Studio óṣèrè lọkunrin ni New York City labẹ akoso Elia Kazan[3].

Lati ọdun 1953 si ọdun 1979, Leachman fẹ̀ George Englund ti wọm si ọmọkunrin mẹrin ati ọmọ óbinrin kan;Bryan (Ọmọ naa ku ni ọdun 1986), Morgan, Adam, Dinah ati George[4][5] .leachman jẹ eni ti kó Kin sin ọlọhun rara[6][7].

Ni óṣu January, ọdun 2021, óṣèrè lóbinrin naa ku si oju órun ni ilè rẹ Encinitas, California lóri aisan stroke ati Covid-19 ti wọn sin ni óṣu february, ọdun 2021[8][9].

Cloris lọsi ilè iwè Theodore Roosevelt. Lẹyin ti óṣèrè lóbinrin naa jade ni ilè iwè ti High ló lọsi ilè iwè giga ti Northwestern[10].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

àtúnṣe

Cloris gba Award ti Primetime Emmy, Ere ti Academy ilẹ British, Golden Globe, Daytime Emmy ati Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[11][12][13].