Complete Sports
Complete Sports logo.jpg | |
---|---|
Type | Daily newspaper |
Format | Broadsheet |
Founder | Sunny Obazu-Ojeagbase |
Publisher | Complete Communications Limited |
Editor | Mumuni Alao Dare Esan Kazeem Tijani |
Editor-in-chief | Sunny Obazu-Ojeagbase |
General manager | Lydia Oyekanmi |
Language | English |
Headquarters | Isolo, Lagos |
Circulation | 124,000 |
Sister newspapers | SuccessDigest Extra |
Official website | completesports.com |
Complete Sports jẹ́ ìwé-ìròyìn eré-ìdárayá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójoojúmọ́, ó sì ní orílé-iṣẹ́ rẹ̀ ní Isolo, ìjọba ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ọdún 1995 ni wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀ ẹ́ jáde gẹ́gẹ́ bí ìwé-ìròyìn ti Complete Communications Limited àti pé ó ti di ọ̀kan lára àwọn ìwé-ìròyìn tó pọ̀ jù lọ ní Naijiria.[1] Ìwé-ìròyìn náà dojú dé sí àwọn eré-ìdárayá Naijiria pàápàá àwọn agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà.
Complete Sports ti pín káàkiri orílẹ̀-èdè Naijiria àti díẹ̀ nínú àwọn agbègbè ti Benin àti Cameroon, nítorí náà, ó mu kí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìwé-ìròyìn tí ó káàkiri jù lọ ní Ìwọ-oòrùn Afirika.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Profile Of Publisher- Complete Sports Magazine In Nigeria". Media Nigeria. 8 November 2012. Retrieved 6 August 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "About Us". Complete Sports. Retrieved 6 August 2015.