Cossy Orjiakor
Cossy Orjiakor (tí a bí ní 16 Oṣù Kẹẹ̀wá) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olùgbéréjáde, akọrin, àti oníjó. Ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn tí ó hàn nínu fídíò orin kan tí Obesere ṣe.[1] Àwọn awuye sì tún wà lóri pé ó maá n fí ọmú rẹ̀ hàn síta tí ó bá wà láàrin àwùjọ àti nígbà tí ó bá n ṣiṣẹ́ ijó rẹ̀ nínu fídíò orin.[2] Ní ọdún 2015, ó ṣe àkọ́kọ́ àgbéjáde fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Power girls, láti ilé-iṣẹ́ rẹ̀ táa pè ní Playgirl pictures.[3]
Cossy Orjiakor | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | October 16 Anambra State |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Nigeria Lagos State University |
Iṣẹ́ | actress, singer, video vixen |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012 - present (acting career) |
Notable work | Papa Ajasco |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeA bí Orjiakor ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.[4][5] Ó parí ilé-ìwé gíga pẹ̀lú gbígba oyè nínu ìmọ̀ ìṣirò àti ìṣàkóso láti Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà ti ìlú Nsukka, ó sì padà tún gba oyè gíga láti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó.[6][7]
Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeOrjiakor jẹ́ ẹni tí àwọn èyàn mọ̀ fún fífi ọmú rẹ̀ hàn síta láàrin àwùjọ. Ó ṣe àpèjúwe ọmú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ore ńlá láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ó sì sọ́ di mímọ̀ wípé òun kì yóò fún àwọn ọmọ òun lọ́mú bí alárà.[8] Awuyewuye sì tún wà lóri pé ṣíṣí igbá àyà rẹ̀ síta lékún n tó fi tètè di ìlúmọ̀ọ́ká.[9] Ìwé ìròyìn Daily Post àti Vanguard ṣe àpéjúwe rẹ̀ bi òṣèré onirawọ ọmu ti Nollywood.[10][11] Nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú Ìwé ìròyìn Encomium, ó ṣàlàyé wípé ṣíṣe ìyá àwọn ọmọ òun mú lẹ̀mí òun ju níní ọkọ lọ.[12]
Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀
àtúnṣeOrjiakor ti ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríṣiríṣi eré ìdárayá.[13] Ó ti ṣe ìfihàn nínu àwọn fídíò orin àti fíìmù, ó sì ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ orin.Ó ṣe àgbéjáde àkọ́kọ̀ àkójọpọ̀ àwon orin rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Nutty Queen ní ọdún 2013, èyítí ó ṣàlàyé wípé ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ pàtàkì nínú.[14] Ó sọ di mímọ̀ wípé òun kò dédé máa ṣí ara òun sílẹ̀ lásán bí kò ṣe pé láti máa fi ṣe ìpolówó ara rẹ̀ ní agbo eré ìdárayá.[15]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- Itohan (didari latọwọ Chico Ejiro ) [16]
- Ara Saraphina
- Anini
- Amobi
- Milionu kan omokunrin
- Papa Ajasco
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Cossy Orjiakor: I was well paid for erotic dance for Abass Obesere". Archived from the original on 5 October 2016. Retrieved 25 September 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Cossy Orjiakor Releases Near N*de Photos To Celebrate Her 31st Birthday". Information Nigeria. 19 October 2015. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Chrysanthus Ikeh (20 March 2015). "Cossy Orjiakor ready with her first movie, ‘Power Girls’". Nigeria Entertainment Today. Archived from the original on 6 March 2016. Retrieved 25 September 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "COSSY ORJIAKOR". Naij.com. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Photos From Cossy Orjiakor’s Birthday Celebration". 360nobs.com. Archived from the original on 30 July 2018. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Cossy Orjiakor: I was well paid for erotic dance for Abass Obesere". Archived from the original on 5 October 2016. Retrieved 25 September 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "I am simply sexy and I know it’ – COSSY ORJIAKOR + why I went back to school". encomium.ng. 22 June 2015. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "No breastfeeding for my kids". Vanguard Nigeria. 23 April 2015. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Ayomide O. Tayo (8 August 2015). "Actress says she likes men with banging bodies". pulse.ng. Archived from the original on 5 October 2016. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Fuji artiste, Obesere, opens up on relationship with boobs star, Cossy Orjiakor". dailypost.ng. 20 July 2013. Archived from the original on 12 October 2016. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Cossy’s big joke on marriage". Vanguard Nigeria. 15 May 2016. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Ayomide O. Tayo (8 August 2015). "Actress says she likes men with banging bodies". pulse.ng. Archived from the original on 5 October 2016. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Cossy Orjiakor: I was well paid for erotic dance for Abass Obesere". Archived from the original on 5 October 2016. Retrieved 25 September 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Isi Esene (1 June 2013). "I’m taking Sexual Seduction to the streets" – Cossy Orjiakor speaks". YNaija.com. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "I am simply sexy and I know it’ – COSSY ORJIAKOR + why I went back to school". encomium.ng. 22 June 2015. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Isi Esene (1 June 2013). "I’m taking Sexual Seduction to the streets" – Cossy Orjiakor speaks". YNaija.com. Retrieved 25 September 2016.