Cou-cou
Cou-cou, coo-coo (gẹ́gẹ́ bí ó ti jẹ́ mímọ̀ ní Windward Islands), tàbí fungie tàbí fungi (gẹ́gẹ́ bí ó ti jẹ́ mímọ̀ ní Leeward Islands àti Dominica) jẹ́ ará oúnjẹ orílẹ̀-èdè national dishes ti Antigua and Barbuda, Barbados, British Virgin Islands àti U.S. Virgin Islands. Ó kún fún cornmeal nìkan (ìyẹ̀fun àgbàdo) àti okra (ochroes).[1] Àgbàdo, ní èyí tí ó máa ń wá ní èyí tí ó ti di ṣíṣe tí ó sì wà ní ilé ìtajà supermarkets islandwide, àti ilá , eléyìí tí ó lè di rírí ní àwọn ilé ìtajà , àwọn ọjà ẹ̀fọ́ àti àwọn ọgbà ilé, jẹ́ àwọn ohun èlò tí kò wọ́n púpọ̀. Nítorí pé àwọn èròjà yìí kò wọ́n, oúnjẹ náà di ohun tó wọ́pọ̀ láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùgbé Barbados ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìtàn ìgbésí ayé ìmúnisìn. Ní Ghana, oúnjẹ tí ó fara jọ ọ́ tàbí ẹbu àgbàdo tí a jẹ pẹ̀lú ọbẹ̀ ilá àti ẹja ni a mọ̀ sí banku, oúnjẹ ààyò ti àwọn ẹ̀yà Ga ní Accra.
Ohun èlò ìdáná tí wọ́n ń pè ní "igi cou-cou", tàbí "igi fungie", jẹ́ ẹ̀yà igi tí wọ́n ń lò fún ìpèlò rẹ̀. Igi Cou-cou jẹ́ èyí tí a ṣe láti ara pákó,tí ó sì ní ìrísí tí ó gùn, tí ó sì pẹlẹbẹ bí {{convert|1|ft|cm|adj=mid|-long}} miniature cricket bat. Ó di gbígbà gbọ́ láti ọwọ́ àwọn Barbadian pé ó ṣe kókó ni ríro cou-cou, gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ náà se máa ń gẹ́lẹ́ àti igi cou-cou máa ń mú un rọrùn láti rò lórí ìkòkò ńlá.
Flying fish tí a sè ní gbígbẹ tàbí bọ̀ jẹ́ àmúpé fún cou-cou. Cou-cou àti ẹja ti di oúnjẹ orílẹ̀-èdè fún àwọn Barbados national dish. Ní àbáláyé, ọjọ́ Ẹtì ni wọ́n máa ń jẹ́ cou-cou ní ilé ní gbogbo Barbados àti ṣíṣe oúnjẹ ìbílẹ̀. Cou-cou tún lè di ṣíṣè nípa lílo breadfruit dípò lílo àgbàdo .
Ní Trinidad and Tobago, cou-cou (tàbí coo-coo) sábàá máa ń di ṣíṣè pẹ̀lú callaloo àti bóyá ata tàbí ẹja gbígbẹ.
Ní àwọn erékùṣù kan, bí Barbados, Antigua, tàbí ní Virgin Islands, cou-cou lè di ṣíṣè láìsí ilá, tí orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ fengi, fungie, tàbí fungi.