Cynthia McKinney
Olóṣèlú
Cynthia Ann McKinney (ojoibi March 17, 1955) je alakitiyan ati oloselu are Amerika. Pelu egbe oloselu Democratic Party, o lo igba mefa ni Ile awon Asoju Orile-ede Amerika lati 1993 de 1997, 1997 de 2003 ati lati 2003 de 2005. Ni 2008, egbe oloselu Alawoewe Orile-ede Amerika pe McKinney fun ipo Aare Orile-ede Amerika ninu idiboyan igba na. Ohun ni obinrin alawodudu akoko to soju fun ipinle Georgia ni Ile Asofin.[1]
Cynthia McKinney | |
---|---|
Former Member of the U.S. House of Representatives from Georgia's 4th District | |
In office January 3, 2005 – January 3, 2007 | |
Asíwájú | Denise Majette |
Arọ́pò | Hank Johnson |
In office January 3, 1997 – January 3, 2003 | |
Asíwájú | John Linder |
Arọ́pò | Denise Majette |
Member of the U.S. House of Representatives from Georgia's 11th District | |
In office January 3, 1993 – January 3, 1997 | |
Asíwájú | None — district created |
Arọ́pò | John Linder |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Cynthia Ann McKinney 17 Oṣù Kẹta 1955 Atlanta, Georgia |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic (1986–2007) Green Party (2007–present) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Coy Grandison (divorced) |
Residence | Lithonia, Georgia |
Alma mater | University of Southern California and Tufts University |
Occupation | high school teacher, college professor |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Jim Lehrer (October 31, 1996). "Georgia on Her Mind". PBS. Archived from the original on July 24, 2013. https://web.archive.org/web/20130724094439/http://www.pbs.org/newshour/bb/election/october96/mckinney_10-31.html.