Hank Johnson
Olóṣèlú
Henry C. "Hank" Johnson Jr. (ojoibi October 2, 1954) je oloselu ara Amerika ati Asoju Ile Asofin Amerika fun àgbègbè iléaṣòfin Georgia 4k, lati 2007. O je omo Egbe Demokratiki.
Henry C. "Hank" Johnson Jr. | |
---|---|
Member of the U.S. House of Representatives from Georgia's 4th district | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga January 3, 2007 | |
Asíwájú | Cynthia McKinney |
Arọ́pò | Incumbent |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹ̀wá 1954 Washington, D.C. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mereda Davis Johnson |
Residence | Lithonia, Georgia |
Alma mater | Clark Atlanta University, Texas Southern University |
Occupation | Attorney |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |