Dámilọ́lá Adégbìtẹ́
Dámilọ́lá Adégbìtẹ́ tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìdínlógún oṣù Karùún ọdún 1985 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti Model. Ó kópa gẹ́gẹ́ bí 'Thelema Duke nínú eré onígbà-dégbà ti Tinsel, àti gẹ́gẹ́ bí emi Williams nínú eré Flower Girl. Ó gba amì-ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tí ó peregedé jùlọ fún àwon eré alátìgbà-dégbà ti 2011 Nigeria Entertainment Awards.[1][2]
Dámilọ́lá Adégbìtẹ́ | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | úwádámilọ́lá Adégbìtẹ́ 18 Oṣù Kàrún 1985 Súrùlérè, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | (1985–present) |
Iṣẹ́ | Òṣèré, model, TV host |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Olólùfẹ́ | Chris Attoh (m. 2015–2017) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Ìbérẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWón bí Dámilọ́lá ní ìlú Sùúrùlérè ní Ìpínlẹ̀ Èkó }. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Queen's College ní ìlú in Yábàá ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti Bowen University ní in Ìlú Ìwó ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀Ṣun. Eré Tinsel ni ó sọọ́bdi ìlú mọ̀ọ́ká. Ó. Sì tún ń kópa nínú ìpolówó ọjà ọlọ́kan-ò-jọkan.[3]
Ìṣẹ̀mí rẹ̀
àtúnṣeNí inú oṣù Kẹ́jọ ọdún 2014, Dámilọ́lá di olólùfẹ́ òṣèré kan Chris Attoh, tí wọ́n jọ ń kópa nínú eré Tinsel.[4] Wọ́n bímọ ní inú ọdún oṣù kẹsàán ọdún 2014 kqn náà tí wọn sì sọ orúkọ ọmọ náà ní Brian.[5] Adégbìtẹ́ àti Atror ṣe ìgbéyàwó bòńkẹ́lẹ́ ní ìlù Accra, tí ó jẹ́ olú-ìlú Ghana ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Kejì ọdún 22015.[6] Ní inú oṣù Kọkànlá ọdún 2017, ìròyìn gbòde wípé ìgbéyàwó Adégbìtẹ́ àti Attoh ti forí ṣọ́pọ́n. In September 2017. [7] [8]
Àwọn fíímù rẹ̀
àtúnṣeÀwọn àsàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- 6 Hours To Christmas (2010)
- Flower Girl (2013)
- Heaven's Hell (2015)
- Isoken (2017)
- Banana Island Ghost (2017)[9]
- The Missing (2017)[10]
- From Lagos with Love (2018)
- Merry Men: The Real Yoruba Demons (2018)
- Merry Men 2: Another Mission (2019)
- Coming From Insanity (2019)
Àwọn ètò rẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán
àtúnṣeTheatre
àtúnṣe- The V Monologues
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ Adeola Adeyemo (29 September 2012). "Bella Naija interviews Damilola Adegbite". Bella Naija. Retrieved 9 February 2014.
- ↑ Yemisi Suleiman (February 12, 2013). "Why I left Tinsel". Vanguard News. Retrieved 9 February 2014.
- ↑ "VMZ Interviews Damilola Adegbite". November 13, 2012. Archived from the original on 23 February 2014. Retrieved 9 February 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "PHOTOS: How Chris Attoh Proposed To Damilola On A Yacht". Peace FM Online. 12 August 2014. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 14 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Aww…Chris Attoh and Damilola Adegbite Christen Their New Son Brian". bellanaija. 23 November 2014. Retrieved 12 March 2015.
- ↑ "Chris Attoh & Damilola Adegbite’s Val’s Day Wedding". Channels Television. 16 February 2015. Retrieved 13 March 2015.
- ↑ "Damilola Adegbite removes husband’s name, unfollows him, and deletes all his photos from IG". Laila's Blog. 25 September 2017. Archived from the original on 26 September 2017. Retrieved 25 September 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Exclusive: Chris Attoh opens up to BellaNaija about New Projects, Divorce from Damilola Adegbite & ‘The Kindness Foundation'". bellanaija. 25 September 2017. Retrieved 25 September 2017.
- ↑ "Banana Island Ghost Full Cast". Uzomedia. Retrieved 2017-05-20.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Clifford, Igbo. "Damilola Adegbite Biography, Age, Early Life, Family, Education, Career, Net Worth And More". Information Guide Africa. Retrieved 2020-04-12.