Dachra
Dachra jẹ́ fíìmù abanilẹ́rù ti orílẹ̀-èdè Tunisia ní ọdún 2018, Abdelhamid Bouchnakni ó kọ ọ́ tí ó sì darí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí fíìmù àkọ́kọ́ tí ó máa jẹ́ akópa nínú ẹ̀
Dachra | |
---|---|
Fáìlì:Dachra-tunisian-movie-poster-md.jpg Poster | |
Adarí | Abdelhamid Bouchnak |
Olùgbékalẹ̀ | Abdelhamid Bouchnak Omar Ben Ali |
Àwọn òṣèré |
|
Orin | Rached Hmaoui Samy Ben Said |
Ìyàwòrán sinimá | Hatem Nechi |
Olóòtú | Abdelhamid Bouchnak |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 113 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Tunisia |
Èdè | Arabic |
Owó àrígbàwọlé | $69,010 |
Àhunpọ̀ ìtàn
àtúnṣeÀwọn akẹ́kọ̀ọ́ oníròyìn, Yasmine, Walid and Bilel, gbéra láti ṣe ìwádìíẹjọ́ tí ọjọ́ tí pẹ́ lórí ẹ̀fún iṣẹ́ àkànṣe fíìmù ilé ẹ̀kọ́.Lẹ́yìn ṣíṣe àbẹ̀wò sí ilé ìwòsàn alárùn ọpọlọ láti fi ọ̀rọ̀ wá Mongia lẹ́nu wò, ẹni tí ó ye ṣíṣá ogun ogún sẹ́yìn,eléyìí ni ó dorí wọn kọ abúlé tí ó ti dahoro.Ki ohun tó ń tó yé wọn yékéyéké,wọ́n bá ara wọn láàárín àwọn àjẹ́ tí ó jẹ ẹran ènìyàn.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Deborah Young (9 September 2018). "Dachra: Film Review, Venice 2018". The Hollywood Reporter. Retrieved 5 August 2021.