Daisy W. Okocha
Daisy Wotube Okocha (tí a bí ní ọjọ́ keedogun oṣù kínní ọdun 1951) jẹ́ Adájọ́ àgbà ìpínlè Rivers, òun ni ó ní ìkáwọ́ High Court of Justice, àti Judicial Service Commission.[1] Gọ́minà Ezenwo Wike ni ó yàn sípò náà ní ọjọ́ kẹrin oṣù kínní ọdun 2016,[2] ó sì di ipò náà mú títí di ìgbà tí ó fi ipò náà kalẹ̀ ní ọjọ́ meedogun oṣù kínní ọdun 2016.[3]
Daisy W. Okocha | |
---|---|
Adájọ́ àgbà keje ti ìpínlè Rivers | |
In office 4 January 2016 – 15 January 2016 | |
Appointed by | Ezenwo Wike |
Asíwájú | Iche Ndu |
Arọ́pò | Adama Lamikanra |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kínní 1951 Obio Akpor, Rivers State |
Profession | Lawyer |
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bi Okocha ní ìlú Obio-Akpor, Ìpínlẹ̀ Rivers, Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ní ọjọ́ keedógún oṣù kínní, Ó jẹ́ ẹ̀yà Ikwerre. Bàbá rẹ̀, Jonathan Okocha, jẹ́ Kọmíṣọ́nà Ọlọ́pá tẹ́lẹ̀ rí, ìyá rẹ̀, Helen Nonyelum Okocha sì ń ta oúnjẹ.[4]
Daisy gba àmì-ẹ̀yẹ ti ìmọ̀ òfin LL.B. (Hons.) ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò ní ọdun 1978. Ní ọdun tí ó tẹ́lẹ̀, ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà, wọ́n gba sínú isẹ́ ìmò òfin.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Chioma, Unini (2016-01-05). "Rivers gets first female chief judge". TheNigeriaLawyer (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.
- ↑ Ihunwo, Tony (2016-01-04). "Governor Wike Swears In First Female Chief Judge In Rivers State, What She Said (PHOTOS)". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.
- ↑ Amadi, Akujobi. "As Justice Okocha Bids Rivers Judiciary Farewell" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.
- ↑ Chioma, Unini (2016-01-05). "Rivers gets first female chief judge". TheNigeriaLawyer (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.