Danny Faure (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù karùn-ún ọdún 1962) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ ède Seychelles láti ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 2016 di ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 2020. Kí ó tó di ààrẹ, òun ni ó jẹ́ igbá kejì ààrẹ Seychelles láti ọdún 2010 di 2016. Faure jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú United Seychelles Party (PP).[2][3]

Danny Faure
4th President of Seychelles
In office
16 October 2016 – 26 October 2020
Vice PresidentVincent Meriton
AsíwájúJames Michel
Arọ́pòWavel Ramkalawan
Vice President of Seychelles
In office
1 July 2010 – 16 October 2016
ÀàrẹJames Michel
AsíwájúJoseph Belmont
Arọ́pòVincent Meriton
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kàrún 1962 (1962-05-08) (ọmọ ọdún 62)
Kilembe, Protectorate of Uganda
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Seychelles Party
(Àwọn) olólùfẹ́Jeanine Decommarmond
(div. 2016)
Shermin Rudie Faure[1]
Àwọn ọmọ5
Alma materUniversity of Havana

Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Faure sí àwọn ìdílé Seychelles tí ó ń gbé ní Ìlú Kilembe tí ó wà ní gúúsù Uganda.[4] Ó ka ìwé prámárì àti Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní Seychelles. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ Sáyẹ́nsì òṣèlú ní Yunifásítì Havana tí ó wà ní Cuba,[5][2][3][4][6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Seychelles Vice President and wife divorce". www.seychellesnewsagency.com. 
  2. 2.0 2.1 George Thande Quoting Reuters (16 October 2016). "Danny Faure sworn in as new president of Seychelles". Businessinsider.com. Archived from the original on 12 May 2019. Retrieved 18 October 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. 3.0 3.1 Uranie, Sharon (16 October 2016). "Seychelles' new President: Danny Faure sworn in to office, calls for unity". Seychelles News Agency. Retrieved 18 October 2016. 
  4. 4.0 4.1 "Explorers Directory". www.nationalgeographic.org. Retrieved 2020-05-28. 
  5. "The President - State House Seychelles | Office of the President". www.statehouse.gov.sc (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-24. 
  6. "Danny Faure". Roscongress Building Trust. Retrieved 2020-05-28.