James Alix Michel (ojoibi August 16, 1944) je oloselu ara Ṣèíhẹ́lẹ́sì to ti je politician who has been Aare ile Ṣèíhẹ́lẹ́sì lati 16 Osu Kerin, 2004. Teletele o je Igbakeji Aare labe asiwaju re, Aare France-Albert René, lati 1996 de 2004.

James Alix Michel
Aare ile Ṣèíhẹ́lẹ́sì
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
16 April 2004
Vice PresidentDanny Faure
AsíwájúFrance-Albert René
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹjọ 1944 (1944-08-16) (ọmọ ọdún 80)
Mahé, Seychelles
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLepep
(Àwọn) olólùfẹ́Natalie Michel