David A. Agard Ph.D. jẹ́ ọ̀jọ̀gbón ìmọ̀  Biochemistry àti Biophysics ní University of California, San Francisco. Ó gba oyè àkọ́kọ́ B.S nínú ìmọ̀ Molecular Biochemistry àti Biophysics lati Yale University, ó sí gba oyè Ph.D. rẹ̀ nínú ìmọ̀ biological chemistry lati California Institute of Technology. Iṣẹ́ rẹ̀ dá lórí ìmọ̀ tó péye lórí ìrísí àti iṣẹ́ macromolecular. Ó jẹ́ olùdarí  Institute for Bioengineering, Biotechnology, àti Quantitative Biomedical Research àti pé ó ti gba jẹ́ olùṣèwádìí ti Howard Hughes Medical Institute (HHMI) lati ọdún 1986.

David A. Agard
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
PápáBiophysics
Biochemistry
Cell Biology
Ilé-ẹ̀kọ́California Institute of Technology (1975–1978)
University of California, San Francisco (1980) (1983– )
MRC Laboratory of Molecular Biology (1981)
Ibi ẹ̀kọ́Yale University (B.S., 1975)
California Institute of Technology (Ph.D., 1980)
University of California, San Francisco (Postdoctoral, 1980)
MRC Laboratory (Postdoctoral, 1981–82)
Ó gbajúmọ̀ fúnProtein Folding
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síPresidential Young Investigator's Award[1] (1983–1991)
Sidhu Award for Outstanding Contributions to Crystallography[1] (1986)

Àwọn ẹ̀bùn

àtúnṣe
  • Ọmọ ẹgbẹ́, American Academy of Arts and Sciences (USA, 2009)[2]
  • Ọmọ ẹgbẹ́, National Academy of Sciences (USA, 2007) [3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "David A. Agard, PhD". UCSF Helen Diller Family Comprehensive Cancer Center. University of California San Francisco. Retrieved 16 February 2016. 
  2. "A". Members of the American Academy of Arts & Sciences: 1780–2012. https://www.amacad.org/publications/BookofMembers/ChapterA.pdf. 
  3. "72 new members chosen by academy" (Press release).

Àwọn ajápọ̀ látìta

àtúnṣe