David Brigidi

Olóṣèlú Nàìjíríà

David Cobbina Brigidi jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 1999 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]

David Cobbina Brigidi
Aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2007
Arọ́pòEmmanuel Paulker
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÌpínlẹ̀ Bayelsa

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Congressional Committees". Nigeria Congress. Archived from the original on 2009-11-18. Retrieved 2010-06-24. 
  2. "Senator Brigidi Urges Rehabilitation of Militants". Leadership. 22 July 2008. Retrieved 2010-06-24.