David Ibiyeomie
Olùṣọ́ àgùntàn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
David Ibiyeomie jé iranse Olórun àti okowe ní Orílè-èdè Nàìjíríà, oun ni olùdásílè àti adari ìjo Salvation Ministries(tí o dá kalè ní odun 1997[1]) tí olú ìjo wón wà ní ilu Port-Harcourt, ìpínlè Rivers, Nàìjirià.[2] A bi David Ibiyeomie sí Bonny Island, ìpínlè Rivers ní kokanlelogun, osù kewa, odun 1962(Oct 21, 1962) [3].
David Ibiyeomie | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | David Ibiyeomie 21 Oṣù Kẹ̀wá 1962 Bonny Island, Nigeria |
Iṣẹ́ | Televangelist |
Website | smhos.org |
Ni odun 1996, David Ibiyeomie fé Peace Ibiyeomie gégé bí iyawo, won sì bí omokurin kan tí óún jé David Ibiyeomie Jr. [4]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Pastor David Ibiyiome: A brief history of salvation ministry". Hodaviah Media Channel. 2020-05-01. Retrieved 2022-03-09.
- ↑ "Salvation Ministries – Salvation Ministries". Salvation Ministries – Home of Success. Archived from the original on 2022-03-09. Retrieved 2022-03-09.
- ↑ Okoh, Chiamaka (2017-07-24). "Pastor David Ibiyeomie Biography and Net Worth". BuzzNigeria.com. Retrieved 2022-03-09.
- ↑ Mbantoh, Desemond (2019-04-25). "Pastor David Ibiyeomie Biography, Wife, Children, Ministry, and Net Worth". BEST OF CHRISTIANITY. Retrieved 2022-03-11.