David J. Wineland

(Àtúnjúwe láti David Jeffrey Wineland)

David Jeffrey Wineland[1] (ojoibi February 24, 1944)[2] je asefisiksi elebun Nobel ara Amerika to unsise ni ibi-idanwo fisiksi ni National Institute of Standards and Technology (NIST). Ninu awon ise to unse ni itesiwaju ninu isiseiwoju, agaga ifi laser mu ioni tutuninu apẹ̀rẹ̀ Paul ati ilo awon ioni inu apere lati samulo isise komputa quantum. O gba Ebun Noble ninu Fisiksi ni 2012, pelu Serge Haroche, fun “awon ona tuntun idanwo to se lo lati se iwon ati ifowoyipada awon sistemu quantum kookan”, to je nipa iwadi eruku imole, eyun awon fotoni.[3]

David J. Wineland
David J. Wineland in 2008
ÌbíDavid Jeffrey Wineland
24 Oṣù Kejì 1944 (1944-02-24) (ọmọ ọdún 80)
Milwaukee, Wisconsin, USA
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́National Institute of Standards and Technology
University of Colorado, Boulder
Ibi ẹ̀kọ́University of California, Berkeley
Harvard University
University of Washington
Doctoral advisorNorman Foster Ramsey, Jr.
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (2012)
National Medal of Science (2007)
Schawlow Prize (2001)


  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named r1
  2. "Array of Contemporary American Physicists | David Wineland". Archived from the original on 2013-01-26. Retrieved 2012-10-27. 
  3. "Press release - Particle control in a quantum world". Royal Swedish Academy of Sciences. Retrieved 9 October 2012.  Text "title" ignored (help)