Dayo Okeniyi
Ọládayọ̀ A. Òkéníyì tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Kẹfà ọdún 1988, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti àti sinimá ọmọ oeílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Òun ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Tresh látàrí ipa rẹ̀ tí.ó kó nínú eré 'The Hunger Games'.[1] [2] Òun náà tún ni ẹ̀dá ìtàn and Danny Dyson nínú eré Terminator Genisys.[3]
Dayọ̀ Òkéníyì | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oladayo A. Okeniyi 14 Oṣù Kẹfà 1988 Jos, Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèré orí-ìtàgé |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–present |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Dayọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Jos lóòtọ́, àmọ́ ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú àwọn àbúrò mẹ́rin lẹ́yìn rẹ̀.[4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ fèyìnti láti ilé-iṣẹ́ aṣọ́bodè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ tí ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ lítíréṣọ̀ láti orílẹ̀-èdè Kenya.[5] Òun àti àwọn ẹbí rẹ̀ kó kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ sí ìlú Indiana ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, kí wọ́n tún tó kó lọ sí California ní orílẹ̀-èdè.Amẹ́ríkà bákan náà. [1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ̀kọ́ nínú ìmọ̀ visual communications ní ilé-ẹ̀kọ́ Anderson University (Indiana) ní ọdún 2009.[6] Ṣáájú kí ó tó kópa nínú eré The Hunger Games, Òkéníyì ti ṣiṣẹ́ ní àwọn sinimá ẹsẹ̀-kùkú àti yíya eré ìtàgé. [7] Òkénìyì bẹ̀rẹ̀ sí ń fara hàn nínú àwọn eré oníṣẹ́ bíi: Endless Love, tí ó sì tú kópa nínú eré Terminator Genisys ní ọdún 2015 gẹ́gẹ́ bí Danny Dyson. [8] Ó sì tún ti kópa nínú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan eré NBC bíi Shades of Blue.
Àwọn àṣàyàn fíímù rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Fíìmù | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2011 | Eyes to See | Unknown role | Short film |
2011 | Lions Among Men | Tau | Short film |
2012 | The Hunger Games | Thresh | |
2012 | The World Is Watching: Making the Hunger Games | Himself | |
2013 | The Spectacular Now | Marcus | |
2013 | Runner, Runner | Perdeep | |
2013 | Cavemen | Andre | |
2013 | Revolution | Alec | TV show |
2014 | Endless Love | Mace | |
2015 | Terminator Genisys | Danny Dyson | |
2016 | Good Kids | Conch | |
2016–2018 | Shades of Blue | Michael Loman | Series regular |
2020 | Run Sweetheart Run |
Àwọn amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá
àtúnṣeWon
àtúnṣe- 2013 Nigeria Entertainment Awards – Best International Actor[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Five Questions with Hollywood Rookie Dayo Okeniyi on 'The Hunger Games'". Essence. 2012-03-21.
- ↑ "Dayo Okeniyi Archive - HG Girl On Fire". Archived from the original on 2012-05-08. Retrieved 2012-04-21. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Silver, Marc (January 9, 2016). "Dayo Okeniyi Is Probably The First Nigerian Actor To Be Shot By J-Lo". Text "work NPR" ignored (help)
- ↑ Dayo Okeniyi - IMDb
- ↑ Dayo Okeniyi - Biography
- ↑ Miller, Jenni (March 23, 2012). "Next Factor: The Hunger Games’ Star Dayo Okeniyi". NextMovie.com. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved October 19, 2020.
- ↑ "Dayo Okeniyi Plays ‘The Hunger Games’ As This Week’s Hump Day Hottie". Archived from the original on 2015-09-20. Retrieved 2020-10-19.
- ↑ "So How Does Terminator Genisys Relate To The Original Films". Dread Central. 2014.
- ↑ Damilare Aiki (September 2, 2013). "2013 Nigeria Entertainment Awards: Full List of Winners & Scoop". BellaNaija. https://www.bellanaija.com/2013/09/2013-nigeria-entertainment-awards-full-list-of-winners-scoop/. Retrieved September 30, 2016.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
àtúnṣe
Àdàkọ:Film-actor-stub
Àdàkọ:Nigeria-actor-stub
Àdàkọ:American-actor-stub