Dear Son (fíìmù 2018)
Dear Son (Lárúbáwá: ولدي) jẹ́ fíìmù Tunisia tí a ṣe ní 2018 tí Mohamed Ben Attia jẹ́ olùdarí.A yàn fún ìfihàn níbi àpéjọ àwọn Olùdarí ní Àjọ fíìmù Cannes ní ọdún 2018. [1][2] Fíìmù náà ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ ìkópa Tunisia fún Àṣẹwá fíìmù àgbáyé tó dára jù lọ, ní ibi àmì ẹ̀yẹ akádẹ́mì kéjìléláàádọ́rin, sùgbọ́n wọn kò yàn án.[3][4]
Dear Son | |
---|---|
Fáìlì:Dear Son.png Film poster | |
Adarí | Mohamed Ben Attia |
Olùgbékalẹ̀ | Dora Bouchoucha Fourati |
Àwọn òṣèré | Mohamed Dhrif Mouna Mejri Imen Cherif Zakaria Ben Ayyed |
Orin | Omar Aloulou |
Ìyàwòrán sinimá | Frédéric Noirhomme |
Olóòtú | Nadia Ben Rachid |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Les Films du Fleuve Tanit Films Nomadis Images |
Olùpín | Bac Films |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 100 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Tunisia Belgium France |
Èdè | Arabic |
Àhunpọ̀ ìtàn
àtúnṣeRiadh is about to retire from his work as a forklift operator in Tunis. The life he shares with his wife Nazli revolves around their son Sami, who suffers from repeated migraine attacks while preparing for his high school exams. When he finally seems to be getting better, Sami suddenly disappears.
Àwọn akópa
àtúnṣe- Mohamed Dhrif as Riadh
- Mouna Mejri as Nazli
- Imen Cherif as Sameh
- Zakaria Ben Ayyed as Sami
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Cannes: Directors' Fortnight unveils 2018 line-up". ScreenDaily. https://www.screendaily.com/cannes/-cannes-directors-fortnight-unveils-2018-line-up/5128346.article.
- ↑ "Cannes: Directors' Fortnight Lineup Boasts Colombia's 'Birds of Passage,' Nicolas Cage in 'Mandy'". Variety. 17 April 2018.
- ↑ ""Weldi" de Mohamed Ben Attia présélectionné par la Tunisie dans la course à l'Oscar du meilleur film international 2020". HuffPost Tunisia. 26 August 2019. Retrieved 27 August 2019.
- ↑ Kozlov, Vladimir (27 August 2019). "Oscars: Tunisia Selects 'Dear Son' for International Feature Category". The Hollywood Reporter. Retrieved 27 August 2019.