Dejumo Lewis
Òṣéré orí ìtàgé
Dejumo Lewis (tí wọ́n bí ní ọdún 1943, tó sì kú ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejìlá ọdún 2023) fìgbà kan jẹ́ òṣèrékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó gbajúmọ̀ fún ṣíṣe ẹ̀dá-ìtàn Kabiyesi, nínú fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ The Village Headmaster. Fíìmù yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwon fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí NTA láti ọdún 1968 wọ ọdún 1988, èyí tí àwọn òṣèré bí i Justus Esiri àti Femi Robinson kópa nínú rẹ̀.[1][2][3] [4][5] Lewis kú ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejìlá ọdún 2023, ní ọmọdún ọgọ́rin (80).[6]
Dejumo Lewis | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Àdàkọ:Birth year Lagos State, Colony and Protectorate of Nigeria |
Aláìsí | (ọmọ ọdún 80) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1964–? |
Notable work | The Village Headmaster (1964) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Anne Cooper-Chen (21 April 2006). Global Entertainment Media: Content, Audiences, Issues. Routledge. pp. 107–. ISBN 978-1-135-60783-8. https://books.google.com/books?id=vKWPAgAAQBAJ&pg=PA107.
- ↑ "Village headmaster, Femi Robinson dies at 75". Punch News. Archived from the original on 24 May 2015. Retrieved 23 May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Victor Akande. "‘Village Headmaster’ Esiri dies at 70". thenationonlineng.net. Retrieved 24 May 2015.
- ↑ Nwachukwu Frank Ukadike (1994). Black African Cinema. University of California Press. pp. 116–. ISBN 978-0-520-91236-6. https://books.google.com/books?id=7tkkAc4KRpwC&pg=PA116.
- ↑ "Drama as Ambassador Segun Olusola is buried - Premium Times Nigeria". Premium Times Nigeria. Retrieved 24 May 2015.
- ↑ Ordia, Esther (23 December 2023). "Veteran Actor Dejumo Lewis Passes Away At 80". OSG Olorisupergal. https://olorisupergal.com/304641/celebrity/veteran-actor-dejumo-lewis-passes-away-at-80/.