The Village Headmaster
The Village Headmaster (ltí wọ́n padà sọ di The New Village Headmaster) jẹ́ fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí Olusegun Olusola gbé kalẹ̀, èyí tí Dejumo Lewis ṣàgbéjáde.[1][2] Láti ìbẹ̀rẹ̀, ètò orí rédíò ní ó jẹ́, tí ó wá padà di èyí tí wọ́n ń ṣá̀fihàn ní orí NTA láti ọdún 1968 wọ ọdún 1988.[3] Lára àwọn òṣèrẹ́ tó kópa nínú fíìmù yìí ni Ted Muroko, tó jẹ́ olórí ilé-ìwé náà láti ìbẹ̀rẹ̀.[4][5] FÍìmù yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣeyọrí tó wáyé nínú àwọn fíìmù tí wọ́n ń ṣàfihàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, ní orílẹ̀-èdè náà[6]
The Village Headmaster | |
---|---|
Genre | Drama |
Written by | Olusegun Olusola |
Directed by | Dejumo Lewis |
Starring | Ted Mukoro (Headmaster #1) Femi Robinson (Headmaster #2) Justus Esiri (Headmaster #3) Chris Iheuwa (Headmaster #4) |
Country of origin | Nigeria |
Original language(s) | English Yoruba Nigerian Pidgin |
Production | |
Executive producer(s) | Olusegu Olusola |
Producer(s) | Sanya Dosunmu, Dejumo Lewis |
Production location(s) | Nigeria |
Running time | 45 minutes |
Release | |
Original network | NTA |
Original release | 1964 |
Ní ọdún 2021, wọ́n bẹ̀rẹ̀ àgbéjáde fíìmù náà, pẹ̀lú Chris Iheuwa gẹ́gẹ́ bí olórí ilé-ìwé tuntun.[7]
Àhunpọ̀ ìtàn
àtúnṣeIlẹ̀ Yorùbá, ní ìlú Oja ni ìbùdó ìtàn fíìmù yìí, tí ìtàn náà sì dá lórí ìṣẹ̀lẹ̀ inú àwùjọ àti ipa tí àwọn ìfilélẹ̀ ìjọba ìlú Oja ń ní sí i. Wọ́n ṣàgbéjáde fíìmù yìí lẹ́yìn tí Nàìjíríà gba òmìnira, ó sì jẹ́ fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòran àkọ́kọ́ tó ní àwọn akópa láti ẹ̀yà oríṣiríṣi tó wà ní Nàìjiríà. Wọ́n lo pidgin English mọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì gan-an gan.
Àwọn akópa
àtúnṣe(Orísun[8])
- Ted Mukoro bí i Headmaster #1
- Femi Robinson - Headmaster #2 (ó rọ́pò Mukoro)
- Justus Esiri - Headmaster #3 (ó rọ́pò Robinson)
- Dejumo Lewis - Kabiyesi, Oja's traditional ruler
- Elsie Olushola - headmaster's wife (Clara Fagade)
- Albert Egbe - Lawyer Odunuga
- Ibidun Allison - Amebo, olófòófó ìlú
- Jab Adu - Bassey Okon
- Funso Adeolu - Senior Chief
- Joe Layode - Teacher Garuba
- Charles Awurum[9]
- Albert Kosemasi - Gorimapa[10]
Àgbéjáde
àtúnṣeWọ́n ṣàgbéjáde eré-oníṣe yìí ní ọdún 1958, ó sì wà gẹ́gẹ́ bí ètò orí rédíò kí ó tó wá di ètò oeí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ní NBC TV Lagos (tó wá di NTA). Ó bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu ní ọdún 1968 pẹ̀lú apá mẹ́tàlá títí wọ ọdún 1988.[11]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nwachukwu Frank Ukadike (1994). Black African Cinema. University of California Press. pp. 116–. ISBN 978-0-520-91236-6. https://books.google.com/books?id=7tkkAc4KRpwC&pg=PA116.
- ↑ "Drama as Ambassador Segun Olusola is buried - Premium Times Nigeria". Premium Times Nigeria. 20 July 2012. Retrieved 24 May 2015.
- ↑ Anne Cooper-Chen (21 April 2006). Global Entertainment Media: Content, Audiences, Issues. Routledge. pp. 107–. ISBN 978-1-135-60783-8. https://books.google.com/books?id=vKWPAgAAQBAJ&pg=PA107.
- ↑ "Village headmaster, Femi Robinson dies at 75". Punch News. Archived from the original on 24 May 2015. Retrieved 23 May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Victor Akande. "'Village Headmaster' Esiri dies at 70". thenationonlineng.net. Retrieved 24 May 2015.
- ↑ Timothy-Asobele, S. J. (2003). Nigerian top TV comedians and soap opera. Lagos: Upper Standard Publications. pp. 41–42. ISBN 9783694626. OCLC 55644917.
- ↑ Jide Kosoko Joins Leiws Allison in The Village Headmaster
- ↑ Music and Models Society (2015-05-13). "THE VILLAGE HEADMASTER". MUSIC and MODELS Society (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-13.
- ↑ "Why I keep my wife away from the public –Charles Awurum". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-05-10. Retrieved 2019-11-26.
- ↑ "Another Village Headmaster Star Dies - P.M. News".
- ↑ "I could be on set for 3 months without touching my wife – Dagbolu of Village Headmaster fame". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 24 May 2015. Retrieved 24 May 2015.