A bí Délé Òdúlé tí a bí lọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kọkànlá ọdún 1961 jẹ́ àgbà òṣèré tíátà àti olótùú-àgbà.[1] Ní ọdún 2014, wọ́n yaǹ-án láti gba àmìn-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré Yorùbá ni (Best of Nollywood Awards) fún ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò "Kori Koto".[2] Òun ààrẹ àwọn òṣèré tíátà àti sinimí àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[3]

Dele Odule
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kọkànlá 1961 (1961-11-23) (ọmọ ọdún 62)
Oru-Ijebu, Ijebu North, Ogun State, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́ìmọ̀ tíátà, University of Ibadan
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan
Iṣẹ́
  • Actor
  • thespian
  • film producer
  • film director
Ìgbà iṣẹ́1986–present

Ìgbéayé Délé Òdúlé Ni Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Àti Bí Ó Ti Kẹ́kọ̀ọ́

àtúnṣe

A bí Délé Òdúlé ní ìlú Òrù-Ìjèbù, Ní Ìjọba Ìbílè Ijebu North ti ìpínlẹ Ogun ní ọdún 1961[4].  Ibè ni ó ti ka ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti gíga.[5] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Olùkọ̀ onípele kejì (Teachers' Grade II Certificate) ní Oru kí ó tó tẹ̀síwájụ́ ẹ̀kọ́ ní University of Ibadan, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ níbi tí ó ti ń kọ́ nípa ìmọ̀ tíátà (Theatre Arts.)[6]

Àdàkọ:Inc-filmInc-film

Awọn atokọ ti eré re

àtúnṣe
  • Ti Oluwa Ni Ile (1993)
  • Lakunle Alagbe (1997)
  • Oduduwa (2000)
  • Afonja (2002)
  • Olorire (2003)
  • Ògédé Didùn (2003)
  • Ogbologbo (2003)
  • Suku Suku Bam Bam (2004)
  • Omo Olè (2004)
  • Iwe Akosile (2005)
  • Idajo Mi Tide (2005)
  • Eru Ife (2005)
  • Ó kojá Ofin (2007)
  • Aye Ibironke (2007)
  • Bolode O'ku (2009)
  • Aworo (2012)

References

àtúnṣe