Ti Oluwa Ni Ile
Ti Olúwa Ni Ilẹ̀ jẹ́ eré oníṣe agbéléwò Yorùbá tí alàgbà Túndé Kèlání darí rẹ̀. [1] Wọ́n gvé eré yí jáde ní ọdún 1993, lábẹ́ ilé-iṣẹ́ agbéré-jáde ti Mainframe Films and Television Productions. Eré yí ni ó gbé alàgbà Túndé Kèlání gẹ́gẹ́ bí adarí eré.[2]
Ti Olúwa Ni Ilẹ̀ | |
---|---|
[[File:Fáìlì:Ti Oluwa Ni Ile cover.jpeg|200px|alt=]] | |
Adarí | Tunde Kelani |
Àwọn òṣèré |
|
Ìyàwòrán sinimá | Tunde Kelani |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 93min |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Àwọn òṣèré akópa
àtúnṣe- Kareem Adepoju
- Dele Odule
- Lekan Oladapo
- Yemi Shodimu
- Yetunde Ogunsola
- Oyin Adejobi
- Gbolagbade Akinpelu
- Jide Oyegunle
- Akin Sofoluwe
Àwọn itọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ E. O. Soola; African Council on Communication Education. Nigeria Chapter; University of Nigeria, Enugu Campus. Institute for Development Studies (2007). Communication in global, ICTs and ecosystem perspectives: insights from Nigeria. African Council for Communication Education (Nigeria Chapter), Office of the Director/Editor-in-Chief, Institute for Development Studies, University of Nigeria in association with Precision Publishers. ISBN 978-978-8103-10-3. https://books.google.com/books?id=i2ASAQAAIAAJ.
- ↑ Akinwumi Adesokan (21 October 2011). Postcolonial Artists and Global Aesthetics. Indiana University Press. pp. 87–. ISBN 978-0-253-00550-2. https://books.google.com/books?id=QpaTNfpZxtIC&pg=PA87.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
àtúnṣe- Ti Oluwa Nile , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)