Delele jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ Zimbabwe ni ẹ̀yà Aríwá- Ìlàòrùn Botswana àti ní Àríwá South Africa d jẹ́ oúnjẹ tí a sè pẹ̀lu ewé tí ó ní orúkọ kan náà, tí wọ́n sì máa ń jẹ pẹ̀lú sadza tàbí phaletšhe tàbí Vhuswa. Orúkọ Gẹ̀ẹ́sì fún delele ni "okra".[1] Ilá ni a tún pè ní "derere".[1][2] Tí a sè pẹ̀lu bakini sódà tí a mọ̀ fún yíyọ̀ tí ó máa ń yọ̀. A lè sá delele gbẹ kí a tó sè é, ṣùgbọ́n ní ọ̀pọ̀ ìgbà a máa ń sèé bí a ṣe káa lórí igi rẹ̀ ni. Àdàkọ:Cn

Àwọn ènìyàn Vha-Venda ti South Africa máa ń se ewé Corchorus olitorius ní ọ̀nà tó jọ bí a ṣe ń se Delele yìí. Oúnjẹ yìí máa ń lọ pẹ̀lú vhuswa (ògì tàbí ẹ̀kọ).

Àpèjúwe

àtúnṣe

Ilá jẹ́ èso ọdọọdún tí ó nírun lára tí ó máa ń so lọ́dọọdún tí ó sì ṣe é jẹ A kò gbọdọ̀ da eléyìí pọ̀ mọ́ Delele. Wọ́n yàtọ̀ sí ara wọn.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Zimbabwe Agricultural Journal". Volume 83, Issue 5. Zimbabwe Ministry of Agriculture. 1986. Okra, (Abelmoschus esculentus L. Moench) also known as lady's finger or "gumbo" in the United States of America and "Derere" or "Delele" in Zimbabwe, is an important vegetable grown throughout the tropics. Its edible pods are ... 
  2. Dutiro, C.; Howard, K. (2007). Zimbabwean Mbira Music on an International Stage: Chartwell Dutiro's Life in Music. SOAS musicology series. Ashgate. p. 93. ISBN 978-0-7546-5799-6. https://books.google.com/books?id=pAd8kEWSzKcC&pg=PA93. 
  3. "okra | Description & Uses". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-30.