Denise Zimba
Denise Zimba (bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1988)[1] jẹ́ òṣèré, olórin, oníjó àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè South Africa[2] tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Mary Gumede tí ó kó nínú eré Generations: The Legacy.[3][4] Ó darapọ̀ mọ́ eto V-Entertainment ni ọdún 2013.[5][6][7]
Denise Zimba | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kopano Denise Zimba 10 Oṣù Kọkànlá 1988 North West,South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Tshwane University of Technology |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–present |
Gbajúmọ̀ fún | Generations: The Legacy |
Olólùfẹ́ | James Dean |
Alábàálòpọ̀ | Kea Phiri |
Àwọn ọmọ | 1 |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels | Zimba Entertainment (Former) |
Website | denisezimba.com |
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
àtúnṣeỌdún | Eré | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
2013 | Fly Chix | Herself |
2013–2016 | V-Entertainment | Herself |
2014 | Generations:The Legacy[8] | Mary Gumede |
Àwọn itokasi
àtúnṣe- ↑ "Denise Zimba". tvsa.co.za. Retrieved 25 June 2015.
- ↑ Julie Kwach (11 July 2019). "Denise Zimba biography : age, pregnancy, fiance, husband, high school, generations and Instagram". briefly.co.za. Archived from the original on 29 October 2020. Retrieved 28 October 2020.
- ↑ "5 Facts About Denise Zimba Who Plays Mary Gumede In Generations". BuzzSouthAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-05. Retrieved 2020-08-29.
- ↑ "Denise Zimba". afternoonexpress.co.za. Retrieved 2020-10-07.
- ↑ "Denise Zimba | TVSA". www.tvsa.co.za. Retrieved 2020-08-29.
- ↑ "5 Facts About Denise Zimba Who Plays Mary Gumede In Generations". BuzzSouthAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-05. Retrieved 2020-08-29.
- ↑ "Denise Zimba". afternoonexpress.co.za. Retrieved 2020-10-07.
- ↑ "LOOK: Denise Zimba pens sweet tribute to daughter on 1st birthday". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-07.