Destiny Etiko tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1989 jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣẹ̀rẹ́bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ Òṣẹ̀rẹ́bìnrin tí ó ń dàgbà jù lọ ní àgbàlá sinimá àgbéléwò lédè Òyìnbó ti City People Movie Award for most Promising Actress (English)City People Entertainment Awards lọ́dún 2016.[1]

Destiny Etiko
Ọjọ́ìbíDestiny Etiko
12 Oṣù Kẹjọ 1989 (1989-08-12) (ọmọ ọdún 35)
Ìpínlẹ̀ Enugu, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaNnamdi Azikiwe University
Iṣẹ́Òṣẹ̀rẹ́bìnrin
Ìgbà iṣẹ́2011– títí di àkókò yìí

ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Etiko sí abúlé kékeré kan tí ó ń jẹ́ Udi, ní Ìpínlẹ̀ Enugu lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ẹ̀yà ìgbò ni wọ́n. Etiko kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti garama rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ náà tí ó sìn gbàwé ẹ̀rí, First School Leaving Certificate àti West African Senior School Certificate. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ tíátà ní yunifásítì ti Nnamdi Azikiwe University, ní ìlú Awka.[2]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Etiko bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 2011. Ó di gbajúmọ̀ òṣẹ̀rẹ́ nígbà tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Idemili tí gbajúgbajà olóòtú sinimá àgbéléwò, Ernest Obi ṣe lọ́dún, ṣùgbọ́n tí kò tètè jáde títí di ọdún 2014. but was not released until 2014. Ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò náà mú un wà nínú àwọn adíje àmì ti City People Entertainment Awards. Kí ó tó kópa nínú sinimá àgbéléwò Idemili, Etiko ti kópa ráńpẹ́ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn sinimá àgbéléwò [2]

Àmìn ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Àmìn ẹ̀yẹ Abala Èsì Ìtọ́kasí
2016 City People Entertainment Awards Òṣèrébìnrin tó ń dàgbà sókè jọ lọ́dún náà lábala sinimá àgbéléwò èdè òyìnbó Gbàá [3]

Aṣojú

àtúnṣe

Ilé iṣẹ́ aṣẹ̀ṣọ́ irun, Kesie Virgin Hair gbà á gẹ́gẹ́ bí aṣojú wọn lọ́dún 2019. [4][5]

Àtòjọ àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa

àtúnṣe
  • The prince & I (2019)[6]
  • Heart of Love (2019)
  • My sisters love (2019)
  • Poor Billionaire (2019)
  • Virgin goddess (2019)
  • Queen of love (2019)
  • The Sacred Cowry (2019)
  • The Return of Ezendiala (2019)
  • Barren Kingdom (2019)
  • Pains of the Orphan (2019)
  • Clap of Royalty (2019)
  • The Hidden Sin (2019)
  • Family Yoke (2019)
  • King’s Word (2019)
  • Sound of Evil (2019)
  • My Private Part (2019) as Stella
  • Power of Royalty (2019)
  • Sunset of Love (2019)
  • London Prince (2019)
  • Woman of Power (2019)
  • Tears of Regret (2018)
  • Evil Seekers (2017)
  • Fear of a Woman (2016)
  • 3 Days to Wed (2016)[6]
  • The Storm (2016)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Nigerian actress, Destiny Etiko: Career, Personal Life, Childhood And Early Life". Within Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-12. Retrieved 2019-12-26. 
  2. 2.0 2.1 "Actress Etiko Destiny stuns in bikinis to mark birthday". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-08-12. Retrieved 2019-12-26. 
  3. Showemimo, Adedayo (26 July 2016). "Full List Of Winners at 2016 City People Entertainment Awards". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 16 May 2020. 
  4. Savvy, Blessing ObiezeContributor at TalkGlitz MediaDiscreet WriterAvid ReaderCreativity (2019-11-05). "Destiny Etiko Lands New Endorsement Deal With Kesie_Virgin Hair". talkGlitz.tv (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-26. 
  5. Ejiogu, Chinecherem (2019-11-05). "Destiny Etiko Signs Endorsement Deal With Kesie_Virgin Hair". NaijaDiary (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-26. 
  6. 6.0 6.1 "Destiny Etiko - nlist | Nollywood, Nigerian Movies & Casting". nlist.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-26.