Di'Ja

Akọrin obìnrin

Hadiza Blell, tó ti wá ń jẹ Hadiza Blell-Olo, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Di'Ja, jẹ́ olórin ti orìlẹ̀-èdè Naijiria. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Mavin Records. Ní ọdún 2009, ó gbórin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Rock Steady", tí wọ́n padà yàn gẹ́gẹ́ bíi orin àdákọ Urban/R&B tó dára jù lọ ní 2009 Canadian Radio Music Awards. Yàtọ̀ sí èyí, ó gba ẹ̀bùn Best New Artist award Beat Music Awards ní ọdún 2008.[1][2]

Hadiza
Di'Ja in 2015
Di'Ja in 2015
Background information
Orúkọ àbísọHadiza Blell
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
Years active2002–present
LabelsMavin Records
Associated acts
Websitedijanation.com

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Di'Ja ti gbé ní orílẹ̀-èdè Naijiria, Sierra Leone, United States àti Canada. Ìyá rẹ̀, Asma'u Blell wá láti apá Àríwá ilẹ̀ Naijiria, bàbá rẹ̀, Amb Joseph Blell sì wá láti orílẹ̀-èdè Sierra Leone.

Di'Ja's gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ biology àti psychology.

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ̀ tó gbà

àtúnṣe
Year Event Prize Recipient Result Ref
2014 Nigeria Entertainment Awards Most Promising Act to Watch style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [3]
2009 Canadian Radio Music Awards Best Urban/R&B Single style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [1][2]
2008 Beat Music Awards Best New Artist Herself Gbàá

Àtọ̀jọ orin rẹ̀

àtúnṣe

Orin àdákọ

àtúnṣe
Year Title Album
2008 rowspan="11" style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single
2012 "How Can We Be Friends"
2013 "Dan'Iska (Rudebwoy)"
"Hold On (Ba Damuwa)"
2014 "Yaro"
"Dorobucci"

(with Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks, and Korede Bello)

"Awww"[4]
"Adaobi"[5]

(with Reekado Banks, Korede Bello, and Don Jazzy)

2015 "Looku Looku"
2016 "Take Kiss"[6]
2017 "Air"
2019 “Omotena” "Di’Ja EP"

Àwọn fọ́rán rẹ̀

àtúnṣe
Year Title Album Director Ref
2016 rowspan="3" style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | Non-album single Adasa Cookey [7]
2016 "Falling for You" Unlimited L.A [8]
2014 "Aww" Unlimited L.A

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Abimboye, Micheal (15 February 2014). "Nigerian Entertainment Round-up: Donjazzy's Mavin Records signs on new artiste' Di'Ja". Premium Times. Retrieved 19 March 2014. 
  2. 2.0 2.1 Filani, Omotola (14 February 2014). "Don Jazzy signs female act Di'Ja to Mavin Records". Daily Post Newspaper. Retrieved 19 March 2014. 
  3. Abimboye, Micheal (31 May 2014). "Pop duo, Skuki, reject Nigerian Entertainment Awards nomination". Premium Times. Retrieved 1 June 2014. 
  4. MavinRecords (16 December 2014), Di'Ja - Awww Music Video, retrieved 12 May 2016 
  5. "New Music: Mavins Feat. Di'Ja, Reekado Banks, Korede Bello – Adaobi". Bellanaija. 27 May 2014. Retrieved 1 June 2014. 
  6. "New Music Di'Ja – 'Take Kiss' ft. BabyFresh". Pulse.ng. Joey Akan. 25 January 2016. Archived from the original on 29 January 2016. Retrieved 26 January 2016. 
  7. "Di'Ja Singer is playful and adorable in 'Take kiss' video". Pulse.ng. Joay Akan. 25 January 2016. Archived from the original on 29 January 2016. Retrieved 26 January 2016. 
  8. "Di'Ja, Patoranking Stars become colourful lovers in 'Falling for you' video". Pulse.com.gh. David Mawuli. 2 October 2015. Archived from the original on 11 March 2016. Retrieved 3 February 2016.