Dr SID
Dr SID Sidney Onoriode Esiri jẹ́ olórin ọmọ orílè-èdè Naijiria. A bíi ní ọjọ́ Kínní oṣù karùn-ún ọdún 1980 ní Ikeja, ìpínlè Èkó, orílẹ̀-èdè Naijiria. Ó jẹ́ ẹni tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Dr SID. Ó sì tún jẹ́ ẹni tí ó ń kọ orin sílẹ̀ tí ó tún jẹ́ akọrin.
Dr SID | |
---|---|
Dr SID performing at MTV Africa Music Awards 2014 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Sidney Onoriode Esiri |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kàrún 1980 Ikeja, Lagos State, Nigeria |
Irú orin | Afrobeats |
Occupation(s) | Singer, songwriter |
Years active | 2002–present |
Labels | Trybe Records, Mo' Hits Records, Mavin Records |
Associated acts | D'banj, Don Jazzy, Wande Coal, Tiwa Savage, Lynxxx, Sarkodie (rapper), Ice Prince |
Website | iamdrsid.com |
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeDr sid wá látì ìpìńlẹ̀ Deltá ,ṣùgbọ̀ń ìpìńlẹ́ èkò ńì wọ̀ń bì sì tì ò jẹ́ tì ṣè kèkèrè. Íyá rẹ̀ jẹ̀ ámùńìdàrá tì bábá rẹ́ ṣì jẹ́ ágbá òṣèré tì òsìńjẹ́ Justus Esiri tì ò jẹ́ ọ̀mọ̀ ẹ́gbẹ̀ "Order of the Niger (MON)" ò tun jẹ́ òlòkìkí ńìnù ìpá káń tì ò kò ńìńù órì ré ìtágè káń tì ò ṣì ṣé ,eyan ere kan ti ògbáyìń Ni òrìlẹ́-ẹ́dẹ̀ Náìjìríá ńì ọ̀dùń 1980. SÌD jẹ́ ọ̀mọ̀ ìkẹ́jì ńìń awọ̀ń mẹ́rìń Ti obirinẹ́ bì.látì ìgbá èwé rẹ́ lọ̀tì fẹ́ dí ò ńì entertainer ,ṣùgbọ̀ń ńkáń yí pádà Bi ò ṣé jade ìlè íwé mẹ́sáń ńì Náìjírìá airforce ìyéń Ile iwe awọ̀ń ẹ́ṣọ̀ òfùrùfù[3] ńì ìkẹ́já tì ojẹ́ òlùlù Ìpìnlẹ́ èkò . Lẹ́yìń gbá ńá ńì ò lọ̀ sì ìlé-iwé gìgá University of Ibadan[1]ńì Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látì lọ̀ ká ìmọ̀ ẹ́kọ̀ ńìpá èyìń kì òlèdì dọ̀kìtá èléyìń. Gẹ́gẹ́ bì ẹ́ ńì tì ò fẹ́ráń Ere idaraya ,ṣé ńì ò kò pá ńì ìjò jìjò, eré òrìtágè ńì ílè ìwè bẹ́ ńáńì ò gbá áwọ̀ń èbùń tì ò pọ̀ jáńtìrẹ́rẹ̀.
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeŃì ọ̀dùń 1999
àtúnṣeDr SID dárápọ̀ mọ̀ Trybe Records tì wọ̀ń dá ẹ́gbẹ̀ Trybesmen tì Náìjìrìá hip pop, tì SID ṣì jẹ́ akọ̀rìń. Osi fi ọ̀dù mẹ́tá fì má jò fùń ẹ́gbẹ̀ Trybesmaen.
Ńi ọ̀dùń 2002
àtúnṣeDr SID pádá di ẹ́ńì Ti ò fi ẹ́rọ̀ òhùń lẹ́yìń Igba ti ò dárá pọ̀ mọ̀ ẹ́gbẹ́ Da Trybe wọ̀ń si tun fun ni áfáńì látì dárápọ mọ̀ ọ̀rìń kan ti akọ̀lé rẹ̀ jẹ́ "OYA, Sa sha,2-shitz,Timi,DEL" tì ò sì fì dá rògbòdìyáń lárìn áwòń akọ̀rìń(hip pop) ńi ọ̀dùń 2002. Lẹ́yìń ìgbáńà SID gbè òrìń tìtì ẹ́ jádẹ́ tì ákọ̀lè rẹ́ sì jẹ́ "Dont Stop" tì ò sì jẹ́ álákọ̀kọ̀ ńìńù mẹ́wá tì wọ̀ń gbọ̀ tì wọ̀ń sì fì ṣẹ́ áfiháń rẹ́ lòrì MBI fùń òsẹ́ mẹ́jọ̀. Ò dá iṣẹ́ òrìń kìkọ̀ dùrò látì fìlè párì ìmọ̀ rè ńì ìlè ìwè gìgá fásìtì.
Ńì ọ̀dùń 2004
àtúnṣeDr SID di dọ̀kìtá èléyìń .Ti ò sì lọ̀ sì ìlù òyìńbò tì ò sì bá áwọ̀ń òlòrìń káń ṣìṣẹ́ bì,JJC átì 419 squad, Felix Duje, KAS, R70, D'Prince átì D'banj. Ńì ìgbá tì ò pádá sì ìlẹ́ Ńáìjìrìá ,òdárápọ̀ mọ̀ Lagos State Teaching Hospital[2][3], lẹ́yìń ìgbáńá ńì òlọ̀ fùń ágùńbáńìrọ̀ ńì ìlù Yola ńì Ìpínlẹ̀ Adámáwá. SID bá orìṣìrìṣì ìlé-ìwòsáń ti wọ̀ń tọ̀jù ẹ́yìń sise, ti o sì n bá ìṣè òrìń ẹ́ lò.
Ńì ọ̀dùń 2005
àtúnṣeŃì ọ̀dùń yì SID bẹ́rẹ̀ sìńì lọ̀sì recording studio tì ọ̀sì gbè áwò káń tì ákọ̀lè rẹ́ jẹ̀ "Prognosis " tì ò ṣè áfìháń "Raise da rof" ńìńù áwò ńáá. Wọ̀ń mù fùń èbùń káń gẹ́gẹ̀ bì òlòrìń tí ò ṣẹ́bẹ́rẹ̀ tì ò sì gbá látì áwọ̀ń tì wọ̀ dá áyẹ́yẹ́ lẹ́ (Amen Award ) Ńì ọ̀dùń 2006 ò gbè ọ̀rìń àwò yì kálẹ́.
Ńì ọ̀dùń 2007
àtúnṣeLẹ́yìń ọ̀dùń mẹ́tá , Dr SID rò pè ọ̀hùń yi ò fi íṣẹ́ itọ̀jù éyìń kálẹ́ tì ò si gbájùmọ̀ ìṣẹ́ òrìń ńì kìkọ̀ tì Don Jazzy ṣì gbá wọ̀lè tì ò sì tùń ṣè áwò káń tì ákọ̀lè rẹ́ ṣì jẹ́ " Curriculum vitae " ńì ábẹ Mo Hitz Allstar . Tì ò sì ṣẹ́ áfìháń márùń dì lògùń òrìń sì ìńù rẹ́ tì "Booty Call átì Close to you " jẹ́ káń lárá ẹ́.
Ńì ọ̀dùń 2009
àtúnṣeDr SID bẹ́rẹ́ si ńì kọ̀rìń Bi akọ̀rìń solo ńì ábẹ́ Mo'Hits Records tì Don Jazzy jẹ́ producer rẹ́. Ákọ̀kò ńìńù álbùmù yì ,tì ákọ̀lé rẹ́ sìjẹ́ "Something About You"[4] tì ò sì jádè ńì ọ̀dùń 2009 tì osì gbè Awọ̀ń áláwọ̀ dùdù gá[5] átì winchi winchi átì wande Coal átì Pop Something ft D'banj kọ̀. Dr SID gbá ámì ẹ́yẹ́ látì ọ́wọ̀ MTV Africa Music Award[6] ńì òrìlẹ́ èdé Kenya gẹ́gẹ́ bì ọ̀mọ̀ ẹ́gbẹ́ Mo'Hitzstars átì D'banj, Wande Coal ńì wọ̀ń jọ̀ gbá ámì ẹ́yẹ̀ yì.
Ńì ọ̀dùń 2014
àtúnṣeNi ọ̀dùń yi wọ̀ń Ti mọ̀ Dr SID tì Moses Inwangs ṣè áfìháń re ninu orin kan ti akọ̀lè rẹ́ jẹ́ "The Last 3 Digit ". Nonso Diob ṣè áfìháń re ninu ere ori itage kan ti akọ̀lè re jẹ̀ "NYSC corp member " tì èré yì sì gbá ere tì ò dájù ń ìlẹ́ ọ̀yá ńì ọ̀dùń yì ńì Parisi òrìlẹ́ édè France.[7][8][9] Dr Sid ṣè live performance ńì Sùrùlérè MTV Africa Awards.
Àwọn àkójọ orin rẹ̀
àtúnṣe- Ní ọdún 2004 :The Big picture
- Ní ọdún 2007: Curriculum Vitae
- Ní ọdún 2012: Solar Plexus
- Ní ọdún 2013 ,DR SID kọ̀ òrìń pẹ́lù áwọ̀ń mẹ́wá rẹ́. 2013 Chocolate West African Remix Ice Prince, Sarkodie, Elom Adablah, and Lynxxx Don Jazzy Chocolate The Remixes
Chocolate East African Remix Musik Maestro Don Jazzy Chocolate The Remixes Afefe Blayze Beats Siduction
Lady Don Dada Don Jazzy Siduction
Love Mine Don Jazzy Siduction
Talented Don Jazzy Siduction
Baby Tornado Don Jazzy Siduction
Baby Tornado Remix Alexandra Burke Don Jazzy Siduction
Surulere Don Jazzy Don Jazzy Siduction
Oyari Tiwa Savage Don Jazzy Siduction
Ńì ọ̀dùń 2015 ńì òkọ̀ Kabiyesi Don Jazzy Single
2016 The Best Don Jazzy single
Flawless Korede Bello Don Jazzy Single
2017 Greater Things Don Jazzy Single
We Up Altims Single
Jensimi Don Jazzy Single
2018 Open and Close Don Jazzy and Altims Single
Softly Solidstar P.Banks Single
40 Bottles Dj Big N, Special Ed, Shody, Do2dtun Princeton Single
Deep Down Seyi Shay Altims Single
2019 Good Time Ozedikus Single
Àwọn àkójọ fídíò rẹ̀
àtúnṣeỌdún tí fídíò yẹn jáde àti àwọn òlùdarí rẹ̀
- 2002 Don't Stop Eldee N/A
- 2009 Something About You Sesan Ogunro N/A
- 2010 Over the moon Dj Tee N/A
Pop Something ft D'banj Walter Banger N/A
- 2011 bamijo ft eldee, Ikechukwu and M.I Sesan Ogunro N/A
- 2013 When this song comes on N/A N/A
- 2012 Afefe Sesan Ogunro N/A
- 2013 Baby Tornado ft Alexandra Burke Olehbuckman Productions N/A
Love Mine Mr Moe Musa N/A
talented Mr Moe Musa N/A
- 2014 Work It ft Navio N/A [15]
- Surulere ft Don Jazzy Daniel Ugo N/A
- 2015 Kabiyesi Dr SID and Adasa Cookey N/A
- 2016 If I Start to talk ft Tiwa Savage Clarence Peters N/A
- The Best Clarence Peters N/A
- Flawless ft Korede Bello Lavinia Noel N/A
- 2017 Jensimi Dr SID and Paul Gambit N/A
- 2018 Open and Close Dr SID N/A
- 2019 Good Time Unlimited LA N/A
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ tí ó ti gbà
àtúnṣe- 2008 Soundcity Music Video Awards Fresh Video Won
- 2009 Nigerian Music Video Awards Best Afro Hip Hop Video[16] Won
- 2011 The Headies Revelation of the year Won
- Best R&B/Pop Album Nominated
Best Pop Single [17] Won
Song of the Year Nominated
Album of the year Nominated
2014 The Headies Song of the year Nominated
Best Collabo Nominated
Best Pop Single Nominated
MTV Africa Music Awards Song of the year Nominated
City People Entertainment Awards [18] Best Collaboration
Àwọn fíímù tí ó ti kòp
àtúnṣe2014 Last 3 Digits Benji Moses Inwang
2015 The Application Director Sidney Esiri
2019 Nigerian Trade Jade Osiberu
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Nigerian Universities, NIgerian Universities
- ↑ Lagos, Lagos Universities.
- ↑ List of hospitals in Nigeria#Lagos, Lagos Hospitals.
- ↑ [1], Something About you Lyrics.
- ↑ [2] Archived 2014-03-31 at the Wayback Machine., Radio Express Africa Chart.
- ↑ [3],[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] MAMA 2009 Performers.
- ↑ "THE LAST 3 DIGITS 1ST TRAILER". You Tube. Moses Inwang. Retrieved 27 October 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "'The Last 3 Digits' Moses Inwang's movie wins 'Best International film' award". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. 4 June 2015. Retrieved 4 June 2015.
- ↑ "Dr. Sid Makes Nollywood Debut In 'The Last 3 Digits'". Information Nigeria. Haliwud. 22 April 2014. Retrieved 22 April 2014.