Dilma Rousseff
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Brazil
(Àtúnjúwe láti Dilma Vana Rousseff)
Dilma Vana Rousseff (Pọrtugí Brasi: [ˈdʒiwmɐ χuˈsɛf], ojoibi December 14, 1947) je oloselu ati Aare orile-ede Brasil tele, lati 1 January 2011 de 31 August 2016. Ohun ni obinrin akoko ti yio bo si ipo yi. Rousseff je onimo oro-okowo. Ni 2005, ohun ni obinrin akoko to di Oga Agba awon Osise Brasil, nigbati Aare Luiz Inácio Lula da Silva yan sipo na.[1]
Dilma Rousseff | |
---|---|
36th President of Brazil | |
In office 1 January 2011 – 31 August 2016 Suspended: 12 May 2016 – 31 August 2016 | |
Vice President | Michel Temer |
Asíwájú | Luiz Inácio Lula da Silva |
Arọ́pò | Michel Temer |
Chief of Staff of the Presidency | |
In office 21 June 2005 – 31 March 2010 | |
Ààrẹ | Luiz Inácio Lula da Silva |
Asíwájú | José Dirceu |
Arọ́pò | Erenice Guerra |
Minister of Mines and Energy | |
In office 1 January 2003 – 21 June 2005 | |
Ààrẹ | Luiz Inácio Lula da Silva |
Asíwájú | Francisco Luiz Sibut Gomide |
Arọ́pò | Silas Rondeau |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Dilma Vana Rousseff 14 Oṣù Kejìlá 1947 Belo Horizonte, Brazil |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Labour Party (1979–1986) Workers' Party (1986–present) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Cláudio Galeno Linhares (1967–1969) Carlos Paixão de Araújo (1969–2000) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Alma mater | Federal University of Minas Gerais Federal University of Rio Grande do Sul University of Campinas |
Signature | |
Website | Official website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Bennett, Allen."Dilma Rousseff biography" Archived 2010-04-09 at the Wayback Machine.. Agência Brasil. August 9, 2010.