Ààrẹ ilẹ̀ Brasil

(Àtúnjúwe láti President of Brazil)

Ààrẹ Brazil tí a mọ̀ sí Ààrẹ orílẹ̀ èdè Brazil (Pọrtugí: Presidente da República Federativa do Brasil) jẹ́ olórí orílẹ̀ èdè Brazil. [1]

Ààrẹ Brasil
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Luiz Inácio Lula da Silva

since 1 January 2023
ResidencePalácio da Alvorada
Iye ìgbàFour years, renewable once
Ẹni àkọ́kọ́Deodoro da Fonseca
Formation15 November 1889
Websitepresidencia.gov.br

Àwọn ààrẹ

àtúnṣe