Djenné

(Àtúnjúwe láti Djenne)

Djenné (bakanna bi Djénné, Jenné ati Jenne) je ilu kekere kan ni agbegbe Delta Niger Inu ti arin orile-ede Mali. Ilu na gbajumo fun awon ile alamo ti won je kiko sibe agaga Mosalasi Olokiki Djenne to je kiko ni odun 1907 ni ori ibi ti mosalasi kan wa tele. Si guusu re ni a ti ri Djenné-Jéno, ibi ti ikan ninu awon ilu pipejulo ni sub-Saharan Africa wa. Djenné je siso di ikan ninu awon Ibi Oso Aye latowo UNESCO ni 1988.

Djenné
Country Mali
RegionMopti Region
CercleDjenné Cercle
Population
 (2009)[1]
 • Total32,944
Old Towns of Djenné*
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO

Great Mosque of Djenné
The Great Mosque
State Party  Mali
Type Cultural
Criteria iii, iv
Reference 116
Region** Africa
Inscription history
Inscription 1988  (12th Session)
* Name as inscribed on World Heritage List.
** Region as classified by UNESCO.


Coordinates: 13°54′20″N 4°33′18″W / 13.90556°N 4.55500°W / 13.90556; -4.55500

  1. Resultats Provisoires RGPH 2009 (Région de Mopti), République de Mali: Institut National de la Statistique, archived from the original on 2010-05-13, retrieved 2010-09-24