Dowen College jẹ kọlẹji ka ti o wa ni Lekki, agbegbe kan ní Eko .

Dowen front view

Kọlẹji naa gba àwon omo tí o wa laarin odun mokanla ai mejidinlogun fún "Day àti boarding".

Ibè ni olorin WizKids ti ya filmu òkan lara àwon orin rè, orin "Hola at your boy".

Ikú Sylvester Oromoni

àtúnṣe

Ni Oṣu Kejila ọdun 2021, àwon Senior Sylvester Oromoni, ọmọ ile-iwe Dowon, èni ti o jé ọmọ ọdun mejila(12) kan lu pa nitori o pinu láti mó darapò mó egbé okunkun. [1] Gege bi baba oloogbe naa se so, won fun ní àwon kemikali láti mu. Leyin iku re, ijoba ipinle Eko ti ile-iwe naa pa titi wón o fi wadi .

Oro náà mu ki àwon onilo ayelujara ma lo hashtag #JusticeForSylvesterOromoni

Àwon ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Dowen College student death - Check all you need to know". https://www.bbc.com/pidgin/media-59527416.