Doyin Òkúpè jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ Òlúrànlọ́wọ́ Àgbà àná lórí ìbáṣepọ̀ àwọn ará ìlú fún Ààrẹ àná orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Goodluck Jonathan láti ọdún 2010 sì 2015.[1][2][3][4] Kí ó tó bá Goodluck Jonathan ṣiṣẹ́, Ààrẹ àná, Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ yàn án lọ́dún 2003 gẹ́gẹ́ bí agbenusọ rẹ̀.[5] Ó ti fìgbà kan díje dupò fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn lábẹ́ àsíyá People’s Democratic Party

Dr. Doyin Òkúpè
IbùgbéAbuja, Nigeria
Iṣẹ́Politics, public affairs
Gbajúmọ̀ fúnSenior Special Assistant Public Affairs to the Nigerian President, Goodluck Jonathan

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe