Dr. Dre
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
(Àtúnjúwe láti Dr Dre)
Andre Romelle Young tí a bí ní ọjọ́ Kejì dín lógún, oṣù Kejì, ọdún 1965 tí ó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ ńjẹ́ Dr. Dre, jẹ́ atọ́kùn àwo orin, [[rapper| afọ̀rọ̀dárà, onígbọ̀wọ́ àwo orin, oníṣòwò, àti lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan bíi òṣèré ará Amẹ́ríkà . Òun ni Olùdásílẹ̀ àti ọ̀gá àgbà Aftermath Entertainment bẹ́ẹ̀ sì ni ó ji fi ìgbà kan rí jẹ́ je onígbọ̀wọ́ fún Death Row Records. Ó ti ṣe olóòtú àwo orin púpọ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn afọ̀rọ̀orindárà ni wọ́n wá láti Ilé-iṣẹ́ rẹ́kọ̀ọ̀dù rẹ̀, àwọn bí i Snoop Dogg, Eminem àti 50 Cent. Gégébí olóòtú àwo orin, ó jẹ́ ẹnìkan pàtàkì tí ó jẹ́ kí orin G-funk West Coast ó gbajúmọ̀.
Dr. Dre | |
---|---|
Dr. Dre backstage at a concert in 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Andre Romelle Young[1] |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kejì 1965 Compton, California, U.S. |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Los Angeles, California, U.S. |
Irú orin | Hip hop, Gangsta Rap |
Occupation(s) | Record producer, rapper, entrepreneur |
Instruments | Vocals, synthesizer, keyboards, turntables, drum machine, sampler |
Years active | 1983–present |
Labels | Priority, Death Row, Aftermath, Interscope, Ruthless |
Associated acts | World Class Wreckin' Cru, N.W.A, Ice Cube, Snoop Dogg, Xzibit, 2Pac, Eminem, 50 Cent, Game |
Website | drdre.com |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |